Posts

Showing posts from September, 2015

Ileri Mimo, Jesu N'temi

Words: Fanny Jane Crosby Ileri mimo, Jesu n'temi; Adun ogo nla, orun didan; Ajogun igbala, omo Olorun; Omo Emi ta fi eje we. Refrain: Eyi nitan mi, atorin mi Ki n ma yin Jesu lojo gbogbo, Eyi nitan mi, atorin mi- Ki n ma yin Jesu lojo gbogbo. Ijewo mimo, ayo didun Iran ayo nla 'be niwaju mi Angel' sokale lati orun Pelu iyin, ayo at'ife Ijewo mimo, mo r'isinmi Ninu Oluwa, mo r'ibukun Mo duro, mo n sona mo n woke Mo kun fun ore at'ife Re Blessed assurance, Jesus is mine; Oh, what a foretaste of glory divine! Heir of salvation, purchase of God, Born of His Spirit, washed in His blood. Refrain: This is my story, this is my song, Praising my Savior all the day long. This is my story, this is my song, Praising my Savior all the day long. Perfect submission, perfect delight, Visions of rapture now burst on my sight; Angels descending, bring from above Echoes of mercy, whispers of love. Perfect submission, all is at res