Ileri Mimo, Jesu N'temi

Words: Fanny Jane Crosby

Ileri mimo, Jesu n'temi;
Adun ogo nla, orun didan;
Ajogun igbala, omo Olorun;
Omo Emi ta fi eje we.

Refrain:
Eyi nitan mi, atorin mi
Ki n ma yin Jesu lojo gbogbo,
Eyi nitan mi, atorin mi-
Ki n ma yin Jesu lojo gbogbo.

Ijewo mimo, ayo didun
Iran ayo nla 'be niwaju mi
Angel' sokale lati orun
Pelu iyin, ayo at'ife

Ijewo mimo, mo r'isinmi
Ninu Oluwa, mo r'ibukun
Mo duro, mo n sona mo n woke
Mo kun fun ore at'ife Re

Blessed assurance, Jesus is mine;
Oh, what a foretaste of glory divine!
Heir of salvation, purchase of God,
Born of His Spirit, washed in His blood.

Refrain:

This is my story, this is my song,
Praising my Savior all the day long.
This is my story, this is my song,
Praising my Savior all the day long.

Perfect submission, perfect delight,
Visions of rapture now burst on my sight;
Angels descending, bring from above
Echoes of mercy, whispers of love.

Perfect submission, all is at rest,
I in my Savior am happy and blest;
Watching and waiting, looking above,
Filled with His goodness, lost in His love.

Comments

Popular posts from this blog

JESU NI BALOGUN OKO

Olori Ijo T'orun

E BA WA YIN OLUWA, ALLELUYA!