E Yin Oba Ogo / Praise The King of Glory

Author: Eliza Edmunds Hewitt

Eyin Oba ogo, Oun ni Olorun
Yin fun 'se 'yanu ti o ti fihan
O wa pelu awon ero mimo l'ona
O si je imole won l'osan l'oru.

Refrain
Eyin Angel 'didan, lu duru wura
Ki gbogbo yin juba, t'e nwo oju re
Ni gbogbo 'joba re, b'aye ti nyi lo
Ise re y'o ma yin
Ise re y'o ma yin
Fi ibukun fun Oluwa okan mi.

E yin fun 'rapada ti gbogbo okan
E yin fun orisun imularada
Fun inu rere ati itoju re
Fun 'daniloju pe O ngbo adura,

E yin fun idanwo bi okun ife,
T'o nso wa po mo awon ohun orun
Fun 'gbagbo ti n'segun , 'reti ti ki sa
Fun ile ogo t'O ti pese fun wa.
Praise the king of Glory, He is God alone,
Praise Him for the wonders He to us hath shown;
For His promised presence, All the pilgrim way,
For the flaming pillar, and the cloud by day.

Refrain:

Praise Him, shining angels, s trike your harps of gold,
All His hosts adore Him, who His face behold;
Through His great dominion, while the ages roll,
All His works shall praise Him/×3
Bless the Lord, my soul!

Praise Him for redemption, free to every soul;
Praise Him for the Fountain that can make us whole;
For His gifts of kindness, and His loving care,
For the blest assurance, that He answers prayer.

Praise Him for the trials, sent as chords of love,
Binding us more closely, to the things above;
For the faith that conquers, hope, that naught can dim,
For the land where loved ones, gather unto Him.

Comments

Popular posts from this blog

JESU NI BALOGUN OKO

Olori Ijo T'orun

E BA WA YIN OLUWA, ALLELUYA!