A nsoro ile bukun ni
Writer: Elizabeth K. Mills
A nsoro ile bukun ni
Ile didan atile ewa N'gba gbogbo la nso togo re Yo ti dun to lati de 'be! A nsoro ita wura re Oso odi re ti ko legbe Faji re ko se fenu so Yo ti dun to lati de 'be! A n so pese ko si nibe Ko saniyan at'ibanuje Pelu 'danwo lode ninu Yo ti dun to lati de 'be A soro orin iyin re Ti a ko le forin aye we, Bo ti wu korin wa dun to Yo ti dun to lati de 'be! A n soro isin ife re Ti agbada tawon mimo nwo Ijo akobi ti oke Yo ti dun to lati de 'be! Jo Oluwa tibi tire Sa se emi wa ye fun orun Laipe awa na yio mo Bo ti dun to lati de 'be
Source: Yoruba Baptist Hymnal #535
|
Source here
|
Great song for great Christians. By the grace of God I must be there.
ReplyDeleteAmen, and me too.
DeleteAwesome and endless classic for many generations to come
ReplyDeleteAwesome hymn
ReplyDeleteAwesome hymn
ReplyDeleteInspirational hymn book
ReplyDeleteBeautiful song if ever there was one. Thanks 🙏
ReplyDeleteVery awesome!
ReplyDeleteReminding us of our time on earth and for those departed love ones. God in His infinity mercy should draw us nearer to Him and help us to note all our days on earth.
Amen!
Delete