Posts

Showing posts from 2018

Laarin Gbungbun Oye/ In The Bleak Midwinter

Image
Author: Christina Rossetti Yoruba Translator: Ayobami Temitope Kehinde Láàrín gbùngbùn ọyẹ́ Ìjì dídì ń sọkún Ayé le bí irin Omi bí òkúta Yìnyín bọ́ lórí yìnyín Lórí yìnyín Láàrín gbùngbùn ọyẹ́ Lọ́jọ́ ọjọ́un Ọlọ́run wa, ọ̀run kò gbàá,  Ayé kò lè gbée ró Ọ̀run, ayé yóò kọjá lọ 'Gb' Ó bá wá jọba. Láàrín gbùngbùn ọyẹ́ Ìbùjẹ́ ẹran tó fún Olúwa Alágbára Jésù Kristi.  Ó tó f' Ẹni tí Kérúbù Ń sìn lọ́saǹ lóru: Ọmú tó kuń fún wàrà Koríko ilé ẹran Ó tó f' Ẹni t'Angel' Ń wólẹ̀ fún o, Màálù, kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́, ràkúnmí Tí ń júbà Rẹ̀ Angel' nípò dépò 'Bá péjọ síbẹ̀ Kérúbù, Séráfù 'Bá wa 'nú afẹ́fẹ́; Ṣùgbọn Màmá Rẹ̀ nìkan, Wúndíá pẹ̀l' áyọ́ Fi ìfẹnukonu Sin Àyànfẹ́. Kínni mo lè fi fún Un, Èmi òṣì, àre Ǹ bá j' olúṣ'àgùntàn, Ǹ bá  fún Un l' ọ̀d'àgùntàn Ǹ bá jẹ́ Amòye Ǹ bá sápá tèmi, — Síbẹ ohun mo ní, mo fún Un, — Ọkàn mi. Trans

Gbogb' Ọkàn Mí Yọ̀ Lálẹ́ Yìí / All My Heart This Night Rejoices

Image
Author: Paul Gerhardt English Translator: Catherine Winkworth Yoruba Translator: Ayobami Temitope Kehinde Gbogb' ọkàn mí yọ̀ lálẹ́ yìí Bí mo tí ń gbọ́ Nílé lóko Ohùn áńgelì dídùn “A bí Krist'”, akọrin ń kọrin Títí i- bi gbogbo Yóò fi rinlẹ̀ fáyọ̀. ‘Jagunsẹ́gun ń jáde lọ lónì í Ó borí ọ̀tá, ẹ̀ṣẹ̀, ’Bìnújẹ́, ’kú, ’pò òkú Ọlọ́run dèèyàn láti gbà wá Ọmọ Rẹ̀, Ó jọ́kan Pẹ̀l' ẹ̀jè wa títí. A ṣì ń bẹ̀rù ’bín' Ọlọ́run, T’Ó fi fún wa Lọ́fẹ̀ ‘Ṣura Rẹ̀ tó ga jù? Láti rà wa padà l'Ó fún wa L’Ọmọ Rẹ̀ Látorí ’tẹ́ Ipá Rẹ ní ọrùn Ó d'Ọ̀dọ́ Àgùntàn t'Ó mú Ẹ̀ṣẹ̀ lọ́ Ó sì ṣe Ìpẹ̀tùsí  kíkún Ó fẹ̀mí Rẹ̀ lélẹ̀ fún wa: Ìran wa Níp' oor'ọ̀fẹ́ Rẹ̀ a yẹ fún ògo. Gbóhùn kan láti ’bùjẹ́ ’ran Dídùn ni, Ó ń bẹ̀bẹ̀, “Sá fún ’dààmú, ewù Ará, ẹ ti gbà ’dásílẹ̀ Lọ́wọ́ ibi, Ohun ẹ nílò Èmi ó fi wọ́n fún yín.” Wá wàyí, lé bànújẹ́ lọ Gbogbo yín, Lọ́kọ̀kan,

Oba aiku, Airi, Orisun Ogbon/Immortal, Invisible God Only Wise

William Cowper, 1731-1800 Oba aiku, airi, orisun ogbon T'O wa n'nu imole toju ko le wo, Olubukunjulo, Ologojulo, Alagbara, Olusegun, 'Wo la yin. Laisimi, laiduro, ni idakeje, O n joba lo, O ko si se alaini; Giga ni idajo Re bi oke nla, Ikuku Re b'isun ire at'ife. O nte gbogbo eda alaye lohun, Nipa imisi Re won gbe igbe won A n dagba, a n gbile bi ewe igi, A si n ro; sugbon bakanaa l'Olorun. Baba nla Ologo, Imole pipe Angeli Re n juba, won bo oju won: Gbogbo 'yin la o mu wa, sa je ka ri O Ka ri olanla imole to bo O. Source: CAC Hymnal #99 Verse 4 retranslated by Ayobami Temitope Kehinde Oct 23, 2018. Immortal, invisible, God only wise, In light inaccessible hid from our eyes, Most blessed, most glorious, the Ancient of Days, Almighty, victorious, Thy great name we praise. Unresting, unhasting, and silent as light Nor wanting nor wasting, Thou rulest in might Thy justice like mountains high soaring above Thy clouds wh

Oluwa Ran Mi Nise/Look and Live

Author: William A. Ogden (1841-1897) Oluwa ran mi ni ‘se, Aleluya! Iwo ni n o je ise na fun; A ko s‘inu Oro Re, Aleluya! P‘eni t‘o ba wo Jesu y‘o ye. Egbe Wo, k‘o ye, Arakunrin, Wo Jesu ki o si ye, A ko s‘inu Oro Re, Aleluya! P‘eni t‘o ba wo Jesu y‘o ye. A ran mi n‘ise ife,  Aleluya!  N o j‘isena fun o ore mi; Ise lat‘ oke wa ni; Aleluya! Jesu so, mo mo pe oto ni. A n‘owo iye si O, Aleluya! A o fi ‘ye ailopin fun O; T‘o ba wo Jesu nikan, Aleluya! Wo o, On nikan l‘o le gbala. Ma wi fun o bi mo se wa, Aleluya! Sodo Jesu to so mi dotun Mo gbagbo n'nu oruko Re, Aleluya! Mo gbekele O si gb'okan mi. Egbe  Source: Verses 1-3 from CAC Hymnal #208 Verse 4 translated by Ayobami Temitope Kehinde, October 23, 2018 I’ve a message from the Lord, hallelujah! This message unto you I’ll give, ’Tis recorded in His word, hallelujah! It is only that you “look and live.” Refrain: "Look and live", my brother live Look to Jesus now, and live; ’T

Gbagbo Awon 'Ya Wa / Faith of Our Mothers

Author:  Arthur Bardwell Patten Gbagbo awon 'ya wa, 'gbagbo aaye Nn' orin at'adura, ale; N' alo at' ife eba ina, Ibagbe re si wa yi wa ka, 'Gbagbo' awon 'ya wa, aaye ni, Ao di o mu titi d'opin. 'Gbagbo awon 'ya wa, aaye ni, 'Bi 'gbekele 't' or'ofe ti nwa Yiya si mimo re ba a le je, 'Bere iran olola nla; Igbagbo 'ya wa, ife ni, Ao di o mu titi d'opin. 'Gbagbo awon 'ya wa nfona han ni, Nnu 'reti at' aigbagbo odo, B'oju at'ona wa tile sookun, T'ao ko tile le r'itoju Re. 'Gbagbo Iya wa, ti Kristi ni, Ao di o mu titi d'opin. 'Gbagbo Iya wa, ti Kristi ni, N'otito to ta 'jewo way o, O ntoju 'le o si gba ijo la, Iwa wa si nf' emi re han; 'Gbagbo 'ya wa ti Kristi ni, Ao di o mu titi d'opin. Source: Yoruba Baptist Hymnal #619 Faith of our mothers, living still  In cradle song and bedtime prayer, In nurs'

Kábíyèsí O, Hòsánnà O

Author: Segun Roberts Kábíyèsí o, hòsánnà o Ẹ yin Jésù Kristì Ọba àìkú Kabiyesi o, hosanna o Ẹ yin Jésù Kristì Ọba àìkú Ègbè Ẹ gbé E ga, Ẹ yin Jésù o Ẹ yin Jésù Kristì Ọba àìkú [Repeat] Wá ká yin Jésù, ará mi ò Ọba mímọ́ Jésù, Ọba àìrí Wá júbà Jésù Olúwa ò Yin Elédùmarè Ọba àìkú Ègbè Ọbańgijì yé o, Olúwa ò Wá gbọpẹ́ wá gba ìyìn àwa ọmọ Rẹ Ángẹ́lì lọ́run ẹ bá wa yìn Ẹ yin Jésù Krístì Ọba àìkú Ègbè Alelúyà sí Ọ Olúwà o Ọpẹ́, ọlá, ìyìn sí Olùbùkún Ho-hosanna, alelúyà o Ẹ yin Jésù Krístì Ọba àìkú Ègbè Unquestionable God, hosanna to You Praise Jesus Christ the immortal King Unquestionable God, hosanna to You Praise Jesus Christ the immortal King Refrain Lift Him up, oh now  praise Jesus Praise Jesus Christ the immortal King Come let’s praise Jesus o my brethren Holy King Jesus, the immortal King Come and worship Jesus the Lord Praise the Almighty, the immortal King Refrain The Most

Láyọ̀, Láyọ̀, La Júbà Rẹ / Joyful, Joyful, We Adore Thee

Image
Author:  Henry J. van Dyke Láyọ̀ láyọ̀, la júbà Rẹ Ológo at' Onífẹ́ Ọkàn wa ṣí bí ododo Ti ń ṣí sí òòrùn lókè Yọ 'kukù ẹ̀ṣẹ̀ o'n 'bànújẹ́ Móòkùn 'yèméjì kúrò Olùfúnni láyọ̀ àìkú Fìmọ́lẹ̀ ọjọ́ kúnnú wa.  Iṣẹ́ Rẹ fayọ̀ yí Ọ  ka Ay' ọ̀run tàn 'tànṣán Rẹ 'Ràwọ̀, áńgẹ́l' ń k ọrin sí  Ọ   Àárín gbùngbùn 'yìn pipe Pápá, igbó, pẹ̀tẹ́lẹ̀, òkè,  Àkùrọ̀, òkun didan Ohùn ẹyẹ, orísun t'ó ń ṣàn  Pè wá latí yọ̀ n'nú Rẹ   Ò ń fifún ni, Ò ń dáríjì  Ol'bùkún, Alábùkún  'Wọ l' orísun ayọ̀ ìyè  Ìjìnlẹ̀ ìsimi 'Wọ Baba wa, Krist' Ẹ̀gbọ́n wa Tirẹ làwọn tó nífẹ̀ẹ́  Kọ́ wá ba ti ń fẹ́ ara wa Gbé wa sáyọ̀ àtòkèwá Ẹ̀dá gbogbo gberin ayọ̀ Táwọn 'ràw' òórọ̀ bẹ̀rẹ̀  Baba 'fẹ́ ń jọba lori wa Ẹ̀gbọ́n 'fẹ́ so wá papọ̀ Lórin títí, a ń tẹ̀ síwájú  Aṣẹ́gun láàrin ìjà Orin ayọ̀ gbé wa sókè N'nú orin &#

Ohun Ipe Kan Ti Oke Petele Wa

Ohun ipe kan ti oke petele wa, S' olotito, 'lotito, 'lotito si Krist, Oke gba orin na, gege b'o ti ndun lo, T' olotito, 'lotito, A! 'lotito si Krist. Refrain Lo si isegun, lo si isegun, Ni ase Balogun wa, Ao lo li ase Re laipe ao gba 'le na Pel' otito, 'lotito, A! 'lotito si Krist. Enyin akin e gbo, iro to mi aiye, S' olotito, 'lotito, 'lotito si Krist, E dide e sise, kede otito na, T' olotito, 'lotito, A! 'lotito si Krist. Wa dapo m' egbe wa, ao Omiran na, S' olotito, 'lotito, 'lotito si Krist, Ao fun ipe ogun, s' ori ogun Esu, T' olotito, 'lotito, A! 'lotito si Krist. A fi agbara wa le Oluwa lowo, S' olotito, 'lotito, 'lotito si Krist, Ao kede 'gbala Re yi gbogbo aiye ka, T' olotito, 'lotito, A! 'lotito si Krist. Source: Yoruba Baptist Hymnal #660

Otito Re Tobi / Great is Thy faithfulness

Author:  Thomas Obadiah Chisholm Otito Re tobi, Bab' Olorun mi, Ko si ayidayida lodo Re; 'Wo ko yi pad' anu Re ko kuna ri, Bi O ti wa, beeni O wa titi. Egbe Otito Re tobi, o tito Re tobi. Laraaro anu tuntun ni mo n ri, Gbogb' ohun mo fe lowo Re ti pese, Otito Re tobi pupo si mi Igba oru, oye, oj' ati 'kore, Orun, osupa, 'rawo lona won Dapo m'eda gbogbo ni ijeri si Otito nla, anu at' ife Re. 'Dariji ese, alafia to daju, 'Walaye Re to n 'tunu to n dari; Agbara fun oni, ireti f' ola, Ibukun ainiye si je temi. Great is Thy faithfulness, o Lord my Father,  There is no shadow of turning with Thee;  Thou changeth not, Thy compassionate they fail not,  As Thou hast been, Thou forever wilt be.  Refrain   Great is thy faithfulness/2x Morning by morning new mercies I see All I have needed Thy hand hath provided. Great is thy faithfulness Lord unto me Summer and winter and s

Gb' ope mi, Oluwa

Gb' ope mi, Oluwa, Lat' okan l' o ti wa, Iwo t' O gba die opo, K'yo kegan 'more mi. Tire ' eran gbogbo, Ti nfo lori oke; Gbogbo 'sura t' o wa l' odo, At' oro 'nu ile. Kini 'ba damu Re? Kil' O fe ti ko si? Apakan ohun t' O fun mi Ko mo mu wa fun O? Ohun idupe ko L' O fe, bi okan wa; Ko s' ohun t' o te O lorun Bi okan imore. Eyi ni mo mu wa, - Okan t' o kun fu je 'fe, O n' iyi l' oju Re j' opo Ore ode okan.