Featured post

KRIST' KI 'JOBA RE DE

Words: Lewis Hensley, 1867 Music: St. Cecilia, Kingsland Krist' ki 'joba Re de, Ki ase Re bere; F' opa-rin Re fo Gbogbo...

Sunday, 18 March 2018

Ohun Ipe Kan Ti Oke Petele Wa

Ohun ipe kan ti oke petele wa,
S' olotito, 'lotito, 'lotito si Krist,
Oke gba orin na, gege b'o ti ndun lo,
T' olotito, 'lotito, A! 'lotito si Krist.

Refrain

Lo si isegun, lo si isegun,
Ni ase Balogun wa,
Ao lo li ase Re laipe ao gba 'le na
Pel' otito, 'lotito, A! 'lotito si Krist.

Enyin akin e gbo, iro to mi aiye,
S' olotito, 'lotito, 'lotito si Krist,
E dide e sise, kede otito na,
T' olotito, 'lotito, A! 'lotito si Krist.

Wa dapo m' egbe wa, ao Omiran na,
S' olotito, 'lotito, 'lotito si Krist,
Ao fun ipe ogun, s' ori ogun Esu,
T' olotito, 'lotito, A! 'lotito si Krist.

A fi agbara wa le Oluwa lowo,
S' olotito, 'lotito, 'lotito si Krist,
Ao kede 'gbala Re yi gbogbo aiye ka,
T' olotito, 'lotito, A! 'lotito si Krist.

Source: Yoruba Baptist Hymnal #660

No comments:

Post a Comment