Posts

Olugbala Gbohun Mi

Words: Fanny Crosby Olugbala gbohun mi Gbohun mi, gbohun mi Mo wa sodo Re gba mi Nibi agbelebu Emi se, sugbon O ku Iwo ku, Iwo ku Fi anu Re pa mi mo Nibi agbelebu Oluwa jo gba mi Nk'y'o bi O n'inu mo Alabukun gba mi Nibi agbelebu Bi n o ba tile segbe N o bebe, n o bebe Iwo ni Ona, iye Nibi agbelebu Ore ofe Re ta gba Lofe ni, lofe ni Foju anu Re wo mi Nibi agbelebu Feje mimo Re we mi Fi we mi, fi we mi Ri mi sinu ibu Re Nibi agbelebu Gbagbo lo le fun wa ni Dariji, dariji Mo figbagbo ro mo O Nibi agbelebu Loving Saviour, hear my cry, Hear my cry, hear my cry; Trembling to Thine arms I fly: O save me at the Cross! I have sinn'd, but Thou hast died, Thou hast died, Thou hast died; In Thy mercy let me hide: O save me at the Cross! Lord Jesus, receive me, No more would I grieve Thee, Now, blessed Redeemer, O save me at the Cross! Tho' I perish I will pray, I will pray, I will pray; Thou of life the Living Way: O

Jesu Ni Gbogbo Aye Fun Mi

Author: Will L. Thompson (1847-1909) Jesu ni gbogbo aye fun mi Iye at'ayo mi Agbara mi lojojumo Laisi Re mo subu Ni'banuje Oun ni mo to Nitori ko s'eni bi Re Ni'banuje O m'ayo wa Ore mi. Jesu ni gbogbo aye fun mi Ore nigba 'danwo Fun ibukun Oun ni mo to Mo ni lopolopo O morun ran, o mojo ro Ikore wura si n po si Orun ojo at'ikore Ore mi Jesu ni gbogb'aye fun mi Nko si ni tan Oun je O ti buru to bi mo se Gbat'Oun ko tan mi je? Ni tito Re nko le sina O n toju mi losan loru Ni tito Re losan loru Ore mi Jesu ni gbogb'aye fun mi Nko fe elomiran N o gbekele nisisiyi T'ojo aye nkoja Aye ewa lodo Re na Aye ewa ti ko lopin Iye, ayo ainipekun Ore mi Jesus is all the world to me, my life, my joy, my all; He is my strength from day to day, without Him I would fall: when I am sad, to Him I go; no other one can cheer me so; when I am sad, He makes me glad; He's my friend. Jesus is all the world to me,

A WE O?

  Elisha Albright Hoffman (1839-1929) O ti to Jesu f'agbara 'wenumo? A we o nin'eje Odo-aguntan? Iwo ha ngbekele oore-ofe Re? Refrain A we O Nin'eje Nin'ej'Od'aguntan fun okan Aso re a funfun o si mo laulau A we o nin'eje Odo-aguntan? O m ba Olugbala rin lojojumo? A we o nin'eje Odo-aguntan? O simi le Eniti a kan mo'gi? A we o nin'eje Odo-aguntan? Aso re funfun lati pad'Oluwa? O mo lau nin'eje Odo-aguntan? Okan re mura fun'le didan loke? Ka we o nin'eje Odo-aguntan? Have you been to Jesus for the cleansing pow’r? Are you washed in the blood of the Lamb? Are you fully trusting in His grace this hour? Are you washed in the blood of the Lamb? Are you washed in the blood, In the soul-cleansing blood of the Lamb? Are your garments spotless? Are they white as snow? Are you washed in the blood of the Lamb? Are you walking daily by the Savior’s side? Are you washed in the blood of the Lamb? Do

TUN MU WA SOJI

W. P. Mackay A yin O'lorun nitor'Omo 'fe Re Fun Jesu ti o ku to si lo soke Halleluyah, tire logo Halleluyah, Amin Halleluyah, Tire logo Tun mu wa soji A yin O'lorun f'emi imole Re To f'Olugbala han t'O mu 'mole wa Ogo ati'yin f'Odaguntan ta pa To mu gbogb'ese wa lo to w'eri wa nu Sa mu wa soji, f'ife Re k'okan wa K'okan gbogbo gbina fun ina orun We praise Thee, O God!  for the Son of Thy love ,  For Jesus who died  and is now gone above. Hallelujah! Thine the glory. Hallelujah! Amen. Hallelujah! Thine thee glory. Revive us again. We praise Thee, O God! F or Thy Spirit of light, Who hath shown us our Saviour,  and scattered our night. All glory and praise  to the Lamb that was slain, Who hath borne all our sins,  and hath cleansed ev’ry stain. Revive us again;  fill each heart with Thy love; May each soul be rekindled  with fire from above.

ARE MU O, OKAN RE PORURU

Edmund Simon Lorenz (1854-1942) Are mu O, okan re poruru? So o fun Jesu: Ibanuje dipo ayo fun o? So o fun Jesu nikan. So o fun Jesu; so o fun Jesu Oun lore ti yoo mo Ko tun sore Ati'yekan bi Re So o fun Jesu nikan Asun-dakun omije lo nsun bi? So o fun Jesu, so o fun Jesu, O l'ese to farasin f'eniyan So o fun Jesu nikan 'Banuje teri okan re ba bi? So o fun Jesu, so o fun Jesu O ha nsaniyan ojo ola bi? So o fun Jesu nikan Ironu iku mu o damu bi? So o fun Jesu, so o fun Jesu Okan re nfe ijoba Jesu bi! So o fun Jesu nikan Are you weary, are you heavy hearted? Tell it to Jesus, tell it to Jesus. Are you grieving over joys departed? Tell it to Jesus alone. Tell it to Jesus, tell it to Jesus, He is a friend that’s well known. You’ve no other such a friend or brother, Tell it to Jesus alone. Do you fear the gathering clouds of sorrow? Tell it to Jesus, tell it to Jesus. Are you anxious what shall be tomorrow? Tell it to Jesus alone.

BO TI DUN LATI GBA JESU

Louisa M. R. Stead, c. 1850-1917 Bo ti dun lati gba Jesu Gbo gege bi oro Re Ka simi lor'ileri Re Sa gbagbo l'Oluwa wi Jesu, Jesu, emi gbagbo Mo gbekele ngbagbogbo Jesu, Jesu, Alabukun Ki nle gbekele O si Bo ti dun lati gba Jesu Ka gbeje wenumo Re Igbagbo ni ki a fi bo Sin'eje 'wenumo na Bo ti dun lati gba Jesu Ki nk'ara ese sile Ki ngb'ayo, iye, isimi Lati odo Jesu mi Mo yo mo gb'eke mi le O Jesu mi, Alabukun Mo mo pe o wa pelu mi 'N'toju mi titi d'opin. ’Tis so sweet to trust in Jesus, Just to take Him at His Word; Just to rest upon His promise, And to know, “Thus saith the Lord!” Jesus, Jesus, how I trust Him! How I’ve proved Him o’er and o’er; Jesus, Jesus, precious Jesus! Oh, for grace to trust Him more! Oh, how sweet to trust in Jesus, Just to trust His cleansing blood; And in simple faith to plunge me ’Neath the healing, cleansing flood! Yes, ’tis sweet to trust in Jesus, Just from sin and self to

KO SORE BI JESU ONIRELE

  Johnson Oatman Jr. (1856-1926) Ko s'ore bi Jesu onirele Ko s'okan! Ko s'okan! Ko s'elomi to le w'okan wa san Ko s'okan! Ko s'okan! Jesu mo gbogbo idaamu wa Yo toju wa d'opin ojo Ko s'ore bi Jesu onirele Ko s'okan! Ko s'okan! Ko s'ore bi Re to ga ni Mimo Ko s'okan! Ko s'okan! Ko s'ore to tutu to n'irele Ko s'okan! Ko sokan! Ko s'akoko ti Oun ko sun mo wa Ko s'okan! Ko s'okan! Ko  s'oru tife Re ko tu won n'nu Ko s'okan! Ko s'okan! Eni kan ha ti r'ore yi nko ni? Ko s'okan! Ko s'okan! Tabe'elese ri ko ni gba oun la? Ko s'okan! Ko s'okan! Ebun kan ha wa bi Jesu fun wa? Ko s'okan! Ko s'okan! Yo ha ko fun wa ka nile l'orun? Ko je ko! Ko je ko! There's not a Friend like the lowly Jesus: No, not one! no, not one! None else could heal all our souls' diseases: No, not one! no, not one! Jesus knows all about our strugg