Posts

Ki Lo Le Wese Mi Nu

Image
Robert Lowry, pub.1876 Ki lo le wese mi nu? Ko si lehin eje Jesu; Ki lo tun le wo mi san? Ko si lehin eje Jesu. Refrain: A! Eje 'yebiye To mu mi fun bi sno, Ko sisun miran mo, Ko si lehin eje Jesu. Fun 'wenumo mi, nko ri, Nkan mi lehin eje Jesu; Ohun ti mo gbekele Fun 'dariji, leje Jesu. Etutu fese ko si, Ko si lehin eje Jesu Ise rere kan ko si Ko si lehin eje Jesu Gbogbo igbekele mi, Ireti mi leje Jesu; Gbogbo ododo mi ni Eje, kiki eje Jesu. br /> Source: Yoruba Baptist Hymnal #23 What can wash away my sin? Nothing but the blood of Jesus; What can make me whole again? Nothing but the blood of Jesus. Oh! precious is the flow That makes me white as snow; No other fount I know, Nothing but the blood of Jesus. For my pardon, this I see, Nothing but the blood of Jesus; For my cleansing this my plea, Nothing but the blood of Jesus. Nothing can for sin atone, Nothing but the blood of Jesus; Naught of good that I have d

Fa Mi Mora

Words: Fanny Crosby Tire lemi se, mo ti gbohun Re O nso ife Re si mi. Sugbon mo fe n'de lapa igbagbo, Ki nle tubo sunmo O Refrain: Fa mi mora, mora, Oluwa Sib'agbelebu t'O ku Fa mi mora, mora, mora Oluwa Sib'eje Re to niye Ya mi si mimo fun ise Tire, Nipa ore-ofe Re: Je ki n fi okan igbagbo woke, Kife mi te siTire. A! Ayo mimo ti wakati kan Ti mo lo nib'ite Re; 'Gba mo gbadura si Olorun mi, Mo ba soro bi ore, Ijinle ife nbe ti ko le mo Titi n o koja odo Ayo giga ti emi ko le so Titi n o fi wa simi, Source: Yoruba Baptist Hymnal #230 I am Thine, O Lord, I have heard Thy voice, And it told Thy love to me; But I long to rise in the arms of faith And be closer drawn to Thee. Draw me nearer, nearer blessed Lord, To the cross where Thou hast died. Draw me nearer, nearer, nearer blessèd Lord, To Thy precious, bleeding side. Consecrate me now to Thy service, Lord, By the power of grace divine; Let my soul look up with a steadfa

E fun'pe naa kikan

Text: Charles Wesley, 1707-1788 E fun'pe naa kikan Ipe ihinrere Ko dun jake jado Leti gbogbo eda; Odun idasile ti de, Pada, elese, e pada Fun 'pe t'Odaguntan Ta ti pa setutu; Je ki agbaye mo Agbara eje Re. Eyin eru ese, E sora yin d'omo, Lowo Kristi Jesu E gba ominira yin. Olori Alufa L'Olugbala i se O fira Re rubo Arukun aruda Okan alare wa, Simi laya jesu: Onirobinuje, Tujuka si ma yo. Blow ye the trumpet, blow! The gladly solemn sound let all the nations know, to earth's remotest bound: The year of jubilee is come! The year of jubilee is come! Return, ye ransomed sinners, home Jesus, our great high priest, hath full atonement made; ye weary spirits, rest; ye mournful souls, be glad: Extol the Lamb of God, the all atoning Lamb; redemption in his blood throughout the world proclaim . Ye slaves of sin and hell, your liberty receive, and safe in Jesus dwell, and blest in Jesus live: Ye who have sold for n

Nigba Tidanwo Yi Mi Ka

Image
Author Unknown Nigba tidanwo yi mi ka Tidamu aye mu mi Ti Esu wa bi ore mi Lati wa iparun mi. Egbe: Oluwa jo ma sai pe mi B'O ti p'Adam' n'nu ogba "Pe nibo lo wa elese?" Nigba t'Esu mu 'tanje re Gbe mi g'or'oke aye, To ni ki n teriba foun Kohun aye je temi, N'gba bilisi fi tulasi Fe mu mi yase Re da To duro gangan lehin mi Nileri pe ko si nkan, Nigba ti mo ba fe topa Damoran o'n fe 'nu mi Tokan mi n se kilakilo, Ti n ko tutu, nko gbona, Nigba ti ko salabaro, Tolutunu si jina, Ti 'banuje ja mi gbongbon Bi iyo ninu okun, Nigba bi aja ti ko gbo Fere ti olode mo, Sonu saginju aye lo Lain' ireti ipada, Nigbati igbekele mi Di togun atorisa, Togede di adura mi, Tofo di ajisa mi, Source: YBH #209 When strong temptations surround me And the world's tempest face me, And Satan came like a friend, Pushing strong for me to fall. Refrain: Saviour please fail not to call me As tho

Onisegun Nla Wa Nihin

By: William Hunter Onisegun nla wa nihin, Jesu abanidaro; Oro Re mu ni lara da A! Gbo ohun ti Jesu! Refrain: Iro didun lorin Seraf', Oruko idun ni ahon. Orin to dun julo ni: Jesu! Jesu! Jesu! A fi gbogbo ese re ji o, A! Gbo ohun ti Jesu! Rin lo sorun lalafia, Si ba Jesu de ade. Gbogb'ogo fun Krist' t'O jinde! Mo gbagbo nisisiyi; Mo foruko Olugbala, Mo fe oruko Jesu. Oruko Re leru mi lo Ko si oruko miran; Bokan mi ti n fe lati gbo Oruko Re 'yebiye. Arakunrin, e ba mi yin, A! Yin oruko Jesu! Arabinrin, gbohun soke A! Yin oruko Jesu! Omode at'agbalagba, To fe oruko Jesu, Le gba 'pe 'fe nisisiyi, Lati sise fun Jesu Nigba ta ba si de orun, Ti a ba si ri Jesu, A o ko 'rin yite ife ka, Orin oruko Jesu. Source: Yoruba Baptist Hymnal #23 The great Physician now is near, The sympathizing Jesus; He speaks the drooping heart to cheer, Oh, hear the voice of Jesus. Sweetest note in seraph song, Sweetest name

Jesu Fe Mi, Emi Mo

Jesu fe mi, emi mo Bibeli so fun mi bee; Tire lawon omode Won ko lagbara, Oun ni. Refrain Ah, Jesu fe mi, Ah, Jesu fe mi, Ah, Jesu fe mi, Bibeli so fun mi . Jesu fe mi, O ti ku Lati si orun sile; Yi o we ese mi nu, Y'o je komo Re wole Jesu fe mi, O fe mi, Bi emi tile saisan, Lor'akete arun mi, O t'ite Re wa so mi. Jesu fe mi, Yi o duro Ti mi lona mi gbogbo: Bi mo ba fe ti mo ku, Yio mu mi rele orun. Poem by Anna Bartlett Warner As originally published in 1860, it appeared in three stanzas, as follows: Jesus loves me—this I know, For the Bible tells me so; Little ones to him belong,— They are weak, but he is strong. Jesus loves me—loves me still, Though I'm very weak and ill; From his shining throne on high, Comes to watch me where I lie. Jesus loves me—he will stay, Close beside me all the way. Then his little child will take, Up to heaven for his dear sake. Hymn by William Batchelder Bradbury   Jesus loves me—this I know,

Okan Mi Yo Ninu Oluwa

Author: E.O. Excell Okan mi nyo ninu Oluwa ‘Tori O je iye fun mi Ohun Re dun pupo lati gbo Adun ni lati r’oju Re Emi yo ninu Re Emi yo ninu Re Gba 'gbogbo lo fayo kun okan mi ‘Tori emi nyo n’nu Re. O ti pe t’O ti nwa mi kiri ‘Gbati mo rin jina s’agbo O gbe mi wa sile l’apa Re Nibiti papa tutu wa Ire at’anu Re yi mi ka Or’ofe Re n san bi odo Emi Re nto, o si nse ‘tunu O n ba mi lo si ‘bikibi Emi y’o dabi Re ni ‘jo kan N o s’eru wuwo mi kale Titi di ‘gbana n o s’oloto Ni sise oso f’ade Re. Amin. Translated by Ayobami Temitope Kehinde Dec 15, 2018. My soul is so happy in Jesus, For He is so precious to me; His voice it is music to hear it, His face it is heaven to see. Refrain: I am happy in Him, I am happy in Him; My soul with delight He fills day and night, For I am happy in Him. He sought me so long ere I knew Him, When wand’ring afar from the fold; Safe home in His arms He hath bro't me, To where there