Jesu Ye Titi Aye
Words: Christian Friedrich Gellert (1715-1769), 1757 Translated by Frances E. Cox (1812-1897), 1841 Tune: St Albinus Jesu ye; titi aiye Eru iku ko ba ni mo; Jesu ye; nitorina Isa oku ko n 'ipa mo. - Alleluya! Jesu ye; lat' oni lo Iku je ona si iye; Eyi y'o je ' tunu wa 'Gbat' akoko iku ba de. - Alleluya! Jesu ye; fun wa l' O ku; Nje Tire ni a o ma se; A o f'okan funfun sin, A o f'ogo f'Olugbala. - Alleluya! Jesu ye; eyi daju, Iku at' ipa okunkun Ki y'o le ya ni kuro Ninu ife nla ti Jesu. - Alleluya! Jesu ye; gbogbo 'joba L'orun, li aiye, di Tire; E ja ki a ma tele Ki a le joba pelu Re. - Alleluya. Source: Yoruba Baptist Hymnal #125 Jesus lives! thy terrors now can no more, O death, appal us; Jesus lives! by this we know thou, O grave, canst not enthrall us. Alleluia! Jesus lives! henceforth is death but the gate of life immortal; this shall calm our trembling breath when we pass its gloomy