Posts

A BAPTIS' WA SINU IKU

Unable to find author A baptis' wa sinu iku, Nipa itebo 'mi; A sin wa 'nu 'boji Jesu, A sin wa pelu Re. A ba Krist' ku k' a ba ye se, K' a le ji pelu Re, K' a le jere ebun titun T' y'o mu wa ye f' oke. Emi, fi ara Re fun wa; K' oro wa ko le je Ireti Oluwa l' oke, At' ifarahan Krist'. Fun igbagbo wa li ogo, Ayo ati ade, Lat' aiye k' a le wa l' oke K' a joko pelu Krist'. Source: Yoruba Baptist Hymnal #377 We are baptised unto His death, By water baptism; And we go down into the grave, Buried with Christ Jesus. Buried with Christ to sin no more, That we may rise in Him, That we may partake of new grace That fits us for the skies. O Holy Ghost, come unto us, That all our words may be The hope of His soon appearing, And Christ's revelation. Lord, let our faith be glorified Our joy and crow fulfil; To live a life of heav'n on earth, On high to reign with the

KRIST' KI 'JOBA RE DE

Words: Lewis Hensley, 1867 Music: St. Cecilia, Kingsland Krist' ki 'joba Re de, Ki ase Re bere; F' opa-rin Re fo Gbogbo ipa ese. Ijoba ife da, Ati t' Alafia? Gbawo ni irira Yio tan bi t'orun? Akoko na ha da, T' ote yio pari, Ika at' ireje, Pelu ifekufe? Oluwa joo, dide, Wa n'nu agbara Re; Fi ayo fun awa Ti o nsaferi Re Eda ngan ooko Re, 'Koko nje agbo Re; Iwa 'tiju pupo Nfihan pe 'fe tutu. Ookun bole sibe, Ni ile keferi: Dide 'Rawo ooro, Dide, mase wo mo. Amin. Source: Yoruba Baptist Hymnal #149 English Thy kingdom come, O God! Thy rule, O Christ begin! Break with thine iron rod the tyrannies of sin! Where is thy reign of peace, and purity and love? When shall all hatred cease, as in the realms above? When comes the promised time that war shall be no more, oppression, lust, and crime shall flee thy face before? We pray thee, Lord, arise, and come in thy great might; revive our lon

Ija D'opin, Ogun Si Tan

Author Unknown Translated from Latin to English by Francis Pott Alleluya! Alleluya!! Alleluya!!! Ija d' opin, ogun si tan: Olugbala jagun molu: Orin ayo l' a o ma ko. Alleluya! Gbogbo ipa n' iku si lo: Sugbon Kristi f' ogun re ka: Aiye E ho iho ayo - Alleluya! Ojo meta na ti koja. O jinde kuro nin' oku: E f' ogo fun Olorun wa. -Alleluya! O d' ewon orun apadi, O s' ilekun orun sile: E korin iyin 'segun Re. - Alleluya! Jesu nipa iya t' O je, A bo lowo iku titi: Titi l' a o si ma yin O. - Alleluya! Source: Yoruba Baptist Hymnal #123 Alleluia, alleluia, alleluia! The strife is o'er, the battle done, the victory of life is won; the song of triumph has begun.  Alleluia! The powers of death have done their worst, but Christ their legions hath dispersed: let shout of holy joy outburst. Alleluia! The three sad days are quickly sped, he rises glorious from the dead: all glory to our risen Head! Allelui

Jesu Ye Titi Aye

Words: Christian Friedrich Gellert (1715-1769), 1757 Translated by Frances E. Cox (1812-1897), 1841 Tune: St Albinus Jesu ye; titi aiye Eru iku ko ba ni mo; Jesu ye; nitorina Isa oku ko n 'ipa mo. - Alleluya! Jesu ye; lat' oni lo Iku je ona si iye; Eyi y'o je ' tunu wa 'Gbat' akoko iku ba de. - Alleluya! Jesu ye; fun wa l' O ku; Nje Tire ni a o ma se; A o f'okan funfun sin, A o f'ogo f'Olugbala. - Alleluya! Jesu ye; eyi daju, Iku at' ipa okunkun Ki y'o le ya ni kuro Ninu ife nla ti Jesu. - Alleluya! Jesu ye; gbogbo 'joba L'orun, li aiye, di Tire; E ja ki a ma tele Ki a le joba pelu Re. - Alleluya. Source: Yoruba Baptist Hymnal #125 Jesus lives! thy terrors now can no more, O death, appal us; Jesus lives! by this we know thou, O grave, canst not enthrall us. Alleluia! Jesus lives! henceforth is death but the gate of life immortal; this shall calm our trembling breath when we pass its gloomy

Jesu N Pe WA L'osan l'oru

Image
Author: Cecil Frances Alexander (1852) Jesu npe wa l' osan, l' oru Larin irumi aiye; Lojojumo l' a ngb' ohun Re Wipe, "Kristian, tele Mi." Awon Apostili 'gbani, Ni odo Galili ni; Nwon ko ile, ona sile, Gbogbo nwon si nto lehin. Jesu npe wa larin lala Aiye wa buburu yi; Larin Afe aiye, O nwi Pe, "Kristian, e feran Mi." Larin ayo at' ekun wa, Larin 'rora on osi, Tantan L' O npe l' ohun rara Pe, "Kristian, e feran Mi." Olugbala, nip' anu Re, Je ki a gbo ipe Re, F' eti 'gboran fun gbogbo wa, K' a fe O ju aiye lo. Jesus calls us: o'er the tumult Of our life's wild, restless sea; Day by day his sweet voice soundeth Saying, "Christian, follow me." As, of old, apostles heard it By the Galilean lake, Turned from home and toil and kindred, Leaving all for his dear sake. Jesus calls us from the worship Of the vain world's golden store, From each idol t

Fun Wa N'le Onigbagbo

Image
Author: B.B McKinney Fun wa n’le onigbagbo Ile ti a nkeko Bibeli Ile ti a nlepa ‘fe Baba Ta f’ewa ife re de lade Fun wa n’le Onigbagbo /2ce Fun wa n’le Onigbagbo Nibi ti Baba j’olotito Ile t’o t’akete si ibi Ile t’o kun f’ayo ‘fe at’orin Fun wa n’le onigbagbo /2ce Fun wa n’le Onigbagbo ‘le t’iya nsise b’oba obinrin Fihan p’ona re lo dara ju Ile ti ngba Jesu l’alejo Fun wa n’le Onigbagbo /2ce Fun wa n’le onigbagbo Ni’bi ti an nto awon omode L’ati mo Kristi t’o feran won Ile t’ina adura tin jo Fun wa n’le onigbagbo /2ce *From Hymn Book for All Churches in Africa: Yoruba & English with Halleluyah Chorus Aroyehun Edition. God, give us Christian homes! Homes where the Bible is loved and taught, Homes where the master’s will is sought, Homes crowned with beauty thy love hath wrought; God, give us Christian homes; God, give us Christian homes! God, give us Christian homes! Homes where the father is true and strong, Homes that are free from the blig

A O Sise!

Words: Fanny J Crosby, 1869 Music: W. Howard Doane, 1871 A o sise ! A o sise! Om'Olorun ni wa, Jek' a tele ona ti Oluwa wa to; K' a f' imoran Re so agbara wa d' otun, K' a fi gbogbo okun wa sise t' a o se. Refrain: Foriti ! Foriti ! Foriti ! Foriti ! K' a reti, k' a s' ona Titi Oluwa yio fi de. A o sise ! A o sise ! Bo awon t' ebi npa, Ko awon alare lo s' orisun iye! Ninu agbalebu l' awa o ma s' ogo, Nigbat' a ba nkede pe, "Ofe n'igbala," A o sise ! A o sise ! Gbogbo wa ni yio se, Ijoba okunkun at'iro yio fo, Ao si gbe oruko Jehofah leke, won, Ninu orin iyin wa pe, "Ofe n'igbala," A o sise ! A o sise !  L'agbara Oluwa, Agbada at'ade yio si je ere wa; Ile awon oloto yio si je ti wa, Gbogbo wa o jo ho pe, "Ofe n'igbala," To the work! to the work! We are servants of God, Let us follow the path that our Master has trod; With the might of His p