Posts

Ona Ara L'Olorun Wa/God Moves in a Mysterious Way

Words: Will­iam Cow­per Ona ara l' Olorun wa Ngba sise Re l' aiye; A nri 'pase Re lor' okun, O ngun igbi l' esin. Ona Re enikan ko mo, Awamaridi ni; O pa ise ijinle mo, O sin se bi Oba. Ma beru mo, enyin mimo, Orun t' o su be ni, O kun fun anu: y'o  rojo Ibukun sori nyin. Mase da Oluwa l' ejo, Sugbon gbeke re le; 'Gbat o ro pe O binu, Inu Re dun si . Ise Re fere ye wan a, Y'o ma tan siwaju; Bi o tile koro loni, O mbo wa dun lola. Afoju ni alaigbagbo, Ko mo 'se Olorun; Olorun ni Olutumo, Y'o m' ona Re ye ni. God moves in a mysterious way His wonders to perform; He plants His footsteps in the sea And rides upon the storm. Deep in unfathomable mines Of never failing skill He treasures up His bright designs And works His sovereign will. Ye fearful saints, fresh courage take; The clouds ye so much dread Are big with mercy and shall break In blessings on you

Gbo 'Gbe Ayo/Hark the Glad Sound

Philip Doddridge, 1702-1751 Gbo 'gbe ayo! Oluwa de, Jesu t' a seleri; Ki gbogbo okan mura de, K' ohun mura ko ' rin O de lati t' onde sile, L' oko eru Esu; 'Lekun 'de fo niwaju Re, Sekeseke 'rin da. O delarin 'baje aiye Lati tan 'mole Re, Lati fun awon afoju N' iriran f' oju  won. O de! 'Tinu f' okan 'rora, Iwosan f' agbogbe; O de pel' opo 'sura Re Fun awon talaka. Hosanna wa, Oba 'lafia Ao kede bibo Re; Gbogbo orun y'o ma korin Oruko t' a feran. Hark the glad sound! The Savior comes, The Savior promised long; Let every heart prepare a throne And every voice a song. He comes the prisoners to release, In Satan's bondage held. The gates of brass before Him burst, The iron fetters yield.   He comes from thickest films of vice To clear the mental ray And on the eyeballs of the blind To pour celestial day.   He c

Baba Orun/Heavenly Father

Author Unknown Translator: Ayobami Temitope Kehinde Baba orun, emi mo iyi Re Baba orun, emi mo iyi Re Mo nife, juba Re Mo wole n’waju Re Baba orun, emi mo iyi Re Omo ’lorun, O ti n’iyanu to Omo ’lorun, O ti n’iyanu to O s’okan wa di mimo Ran Emi Mimo sinu wa Omo ’lorun, O ti n’iyanu to Emi Mimo, itunu nla ni O Emi Mimo, itunu nla ni O O n to wa, O n dari, O n gbenu okan wa Emi Mimo, itunu nla ni O Heavenly Father, I appreciate you Heavenly Father, I appreciate you I love You, adore You, I bow down before you Heavenly Father, I appreciate you Son of God, what a wonder You are Son of God, what a wonder You are You’ve cleansed our souls from sin Sent the Holy Ghost within Son of God, what a wonder You are Holy Ghost, what a comfort You are Holy Ghost, what a comfort You are You lead us, You guide us You live right inside us Holy Ghost, what a wonder You are

Mo Mo Pe Oludande Mi N Be

Author: Jessie Brown Pounds Mo mo pe Oludande mi n be Y'o tun duro ni aye yi Mo mo pe O fun mi ni iye Ore-ofe n be l'owo Re Refrain: Mo mo pe Jesu n be ni aaye Y'o tun duro ni aye yi Mo mo pe O fun mi ni iye Ore-ofe n be l'owo Re Mo mo pe' leri Re ko le ye Oro Re ye titi lailai B'iku tile pa ara mi run Emi yo ri lojukoju Mo mo pe O n pese aye de mi 'Biti O wa l'emi y'o wa O n pa mi mo titi d'igbana O n pada bo lati mu mi Source: Iwe Orin Irapada Ti Ijo Aposteli Naa #776 I know that my Redeemer liveth, And on the earth again shall stand; I know eternal life He giveth, That grace and power are in His hand. Chorus: I know, I know that Jesus liveth, And on the earth again shall stand; I know, I know that life He giveth, That grace and power are in His hand. I know His promise never faileth, The word He speaks, it cannot die; Tho' cruel death my flesh assaileth, Yet I shall see Him by and by< I

Ile Ayo Kikun Kan N Be

Words of verses by Isaac Watts (1709) Words of refrain by Anonymous Ile ayo kikun kan n be Bit' awon mimo n gbe Ko soru af' osan titi Irora ko si be Refrain: Ounje iye ni awa n je Kanga iye ni awa n mu Enit' o ba mu kanga yii Oungbe ki y'o gbe mo lailai Bayi ni Jesu wi, "Oungbe ki y'o gbe mo." Bayi ni Jesu wi, "Oungbe ki y'o gbe mo." Enit' o ba mu kanga yii Oungbe ki y'o gbe mo lailai Orisun iye n be nibe Itanna ti ki re Iku n'iboju ti ko je K'a r'ile ewa yi 'Yemeji wa 'ba le fo lo K'a le aigbagbo lo K'a fi 'gbagbo wo Kenan wa Ile wara, oyin A ba le goke bi Mose K'a wo 'le naa lookan Ikun bi odo nla Jordan K'y'o ba wa leru mo Source: Iwe Orin Irapada Ti Ijo Aposteli Na #782 There is a land of pure delight, where saints immortal reign, infinite day excludes the night, and pleasures banish pain. Refrain: We’re feeding on the living br

Sinmi Le Apa Ayeraye/Leaning On The Everlasting Arms

Image
Anthony J. Showalter and Elisha A. Hoffman , pub.1887 Idapo didun, ayo atoke wa ’Sinmi le apa ayeraye Ibukun pupo, ifokanbale ’Sinmi le apa ayeraye Refrain: Sinmi, sinmi Eru ko ba mi, aya ko fo mi Sinmi, sinmi Sinmi le apa ayeraye Bo ti dun to lati rin ajo yii ’Sinmi le apa ayeraye B'ona na ti n’mole sii lo'jumo ’Sinmi le apa ayeraye N o se wa foya, n o se wa beru, ’Sinmi le apa ayeraye Okan mi bale, Jesu sunmo mi ’Sinmi le apa ayeraye Translated to Yoruba by Ayobami Temitope Kehinde, 2016 What a fellowship, what a joy divine, Leaning on the everlasting arms; What a blessedness, what a peace is mine, Leaning on the everlasting arms. Refrain: Leaning, leaning, Safe and secure from all alarms; Leaning, leaning, Leaning on the everlasting arms. Oh, how sweet to walk in this pilgrim way, Leaning on the everlasting arms; Oh, how bright the path grows from day to day, Leaning on the everlasting arms. What have I to dread, what have I to

Iye Wa Ni Wiwo, Eni Ta Kan Mogi

Words: Miss Amelia Matilda Hull Iye wa ni wiwo, Eni t'a kan mo'gi Iye wa nisisiyi fun o; Nje wo O elese k' o le ri igbala, Wo Enit' a kan mo 'gi fun o. Refrain: Wo! wo! wo k' o ye, Iye wa ni wiwo Enit'a kan mo gi Iye wa nisisiyi fun o. Kil' o se ti On fi dabi Bi a ko gb' ebi re ru Jesu! Eje 'wenumo se san lati iha Re, B' iku Re ko j' etu f' ese re? Ki s' ekun 'piwada ati adura re, Eje na l' o s' etutu f' okan; Gbe eru ese re lo si odo Eni, Ti o tit a eje na sile. Ma siyemeji s' ohun t' Olorun wi, Ko s'ohun t'o ku lati se mo, Ati pe On yio wa nikehin aiye, Y'o si s'asepari ise Re. Nje wa f'ayo gba iye ainipekun, Ni owo Jesu ti fifun ni; Si mo daju pe iwo ko si le ku lai, N'gbati Jesu Ododo re wa. Source: Yoruba Baptist Hymnal #177 There is life for a look at the Crucified One, There is life at this moment for thee; Then look, sinner, look unto H