Posts

Halleluyah, Halleluyah

Writer:  Christopher Wordsworth (1807-1885), 1862 Halleluyah, Halleluyah, E gbe ohun ayo ga, E korin inudidun, K' e si yin olorun wa, Enit'a kan m'agbelebu, T' o jiya fun ese wa; Jesu Kristi Oba ogo Jinde kuro n'nu oku. Irin idabu se kuro Kristi ku, O sit un ye, O mu iye at aiku Wa l'oro ajinde Re; Krist' ti' segun, awa segun Nipa agbara nla Re, Awa o jinde pelu Re, A o ba wo 'nu ogo. Kristi jinde, akobi ni Ninu awon t' o ti sun, Awon yi ni y' o ji dide, Ni abo Re ekeji; Ikore ti won ti pon tan Nwon  nreti  Olukore, Eniti y'o mu won kuro, Ninu isa oku won. Awa jinde pelu Kristi T'O nfun wa l' ohun gbogbo Ojo, iri, ati ogo To ntan jade l' oju Re; Oluwa b' a ti wa l'aiye, Fa okan wa s'odo Re, K'awon maleka saw a jo, Ki  nwon  ko wa d,odo Re. Halleluyah, Halleluyah! Ogo ni fun Olorun; Halleluyah f' Olugbala Enit' Osegun iku.

Krist' Oluwa Ji Loni

Writer:  Charles Wesley Krist' Oluwa ji loni, - Halleluyah, Eda at' Angeli nwi - Hal. Gb' ayo at' isegun ga - Hal. K' orun at' aiye gberin! - Hal. Ise ti idande tan; - Hal. O jija, O ti segun; - Hal. Wo, 'ponju orun koja - Hal. Ko wo sinu eje mo - Hal. Lasan n' iso at' ami, - Hal. Krist' woo run apadi; - Hal Lasan l' agbara iku, - Hal. Krist, si Paradise. - Hal. O tun wa, Oba ogo: - Hal. "Iku itani re wa?" - Hal. Lekan l' O ku k' O gba wa, - Hal. "'Boji, isegun re wa?" - Hal. E je k' awa goke lo, - Hal. Sodo Kristi Ori wa, - Hal. A sa jinde pelu Re, - Hal. Bi a ti ku pelu Re. - Hal. Oluwa t' aiye t' orun, - Hal. Tire ni gbogbo iyin, - Hal. A wole niwaju Re - Hal. 'Wo Ajinde at' Iye. - Hal. Source: Baptist Hymnal #118 Christ the Lord is ris’n today, Alleluia! Sons of men and angels say, Alleluia! Raise your joys an

O KU! ORE ELESE KU / HE DIES! THE FRIEND OF SINNERS DIES!

Writer:  Isaac Watts O ku! - Ore elese ku; Omobirin Salem' sokun; Okunkun bo oju orun, Ile wariri lojiji. Ife at' ikanu l; eyi Oluwa Ogo ku f'enia! Sugbon ayo wo l'a ri yi - Jesu t' Oku tun ji dide! Olorun ko boji sile, O  lo s'agbala Baba Re. Ogun Angeli sin lo 'le, Nwon si fi ayo gba s' oke, Ma sokun mo, enyin mimo, K' e so giga ijoba Re; Korin b' O ti segun Esu, T' O si de iku li ewon. E wipe, "Oba wa titi, Enit' a bi lati gba la!" E b' iku pe, "Oro re da?" Isa-oku, "'Segun re da?" Source: Baptist Hymnal #119 He dies! the Friend of sinners dies! Lo! Salem’s daughters weep around; A solemn darkness veils the skies, A sudden trembling shakes the ground. Come, saints, and drop a tear or two For Him who groaned beneath your load: He shed a thousand drops for you, A thousand drops of richer blood. Here’s love and grief

E JE KA FINU DIDUN

Writer:  John Milton (1608-1674), 1623 E je k' a f' inu didun, Yin Oluwa Olore; Anu Re, o wa titi, L' ododo dajudaju. O'n, nipa agbara Re, F' imole s' aiye titun; Anu Re, o wa titi, L' ododo dajudaju. O mbo awon alaini, Ati gbogbo alaye; Anu Re, o wa titi, L' ododo dajudaju. O bukun ayanfe Re Li aginju iparun; Anu Re, o wa titi, L' ododo dajudaju. E je k' a f' inu didun, Yin Oluwa Olore; Anu Re, o wa titi, L' ododo dajudaju. Source: Baptist Hymnal #79 Let us, with a gladsome mind, praise the Lord, for he is kind: Refrain: for his mercies aye endure, ever faithful, ever sure. Let us blaze his Name abroad, for of gods he is the God: He with all commanding might filled the new-made world with light: He the gold-tressèd sun caused all day his course to run:  The horned moon to shine by night, mid her spangled sisters bright: All things livi

N'nu Krist' Nikan/ In Christ Alone

Authors: Stuart Townend & Keith Getty N'nu Krist' nikan nireti mi, O'n n'imọlẹ, agbar', orin mi; Igun-ile yii, Apata yii, Wa sibẹ nin' ọda 'ti'ji. Ifẹ giga, ibalẹ okan, 'Gbati 'bẹru, idamu pin! Olutunu, Oun ni mo ni, Ninu 'fẹ Kristi mo duro. N'nu Krist' nikan, t'O wa leeyan Ọlọrun to wa bí ìkókó! Ẹbun 'fẹ yii at' ododo T'awọn t'O wa gbala kẹgan: Lori igi ti Jesu ku, Irunu Ọlọrun walẹ- Tori pẹ'ṣẹ wa lo gberu; Ninu 'ku Kristi ni mo ye. Nibẹ 'nu 'lẹ l'oku Rẹ wa Imọlẹ aye t'ookun pa: Lẹyin eyi lọjọ ologo O ji dide kuro 'nu oku! B'O si ti duro n'iṣẹgun Mo bọ lọwọ egun ẹṣẹ, Mo jẹ Tirẹ, Oun temi- Emi ta fẹjẹ Kristi ra. Niye, niku, ko si 'foya, Agbara Kristi 'nu mi ni; Lati 'bẹrẹ titi dopin, Jesu gba ayanmo mi mu. Ogun eṣu, ete aye Ki yoo le gba mi lowo Rẹ, 'Ti y' O fi de, tabi pe mi N o duro 'nu agbara Kristi. Translat

Mo faye atife mi fun/My life, my love I give to Thee

Words: Ralph E. Hudson (1843-1901) Mo f'aye at'ife mi fun Od'aguntan to ku fun mi; Je ki n le je olotito, Jesu Olorun mi. N o wa f'Eni t'O ku fun mi, Aye mi yo si dun pupo; N o wa f'Eni to ku fun mi, Jesu Olorun mi. Mo gbagbo pe Iwo n gbani 'Tori 'Wo ku k'emi le la; Emi yo si gbekele O, Jesu Olorun mi. Iwo t'O ku ni Kalfari, Lati so mi dominira; Mo yara mi soto fun O, Jesu Olorun mi. My life, my love I give to Thee, Thou Lamb of God who died for me; O may I ever faithful be, My Savior and my God! I’ll live for Him who died for me, How happy then my life shall be! I’ll live for Him who died for me, My Savior and my God! I now believe Thou dost receive, For Thou hast died that I might live; And now henceforth I trust in Thee, My Savior and my God! O Thou who died on Calvary, To save my soul and make me free, I’ll consecrate my life to Thee, My Savior and my God!

Elese E Yipada

Image
Words: Charles Wesley Elese e yi pada, Ee se ti e o fi ku? Eleda nyin ni n bere; T' O fe ki e ba On gbe: Oran nla ni O nbi nyin, Ise owo Re ni nyin, A! enyin alailope, Ee se t'e o ko, 'fe Re. Elese e yi pada, Ee se ti e o fi ku? Olugbala ni n bere, Enit' o gb' emi nyin la; Iku Re y'o j' asan bi? E o tun kan mo 'gi bi? Eni 'rapada, ee se Ti e o gan ore Re? Elese e yi pada Ee se ti e o fi ku? Emi Mimo ni n bere Ti nf' ojo gbogbo ro nyin E ki o ha gb' ore Re? E o ko iye sibe? A ti nwa yin pe, ee se T' e n bi Olorun ninu? Iyemeji ha nse nyin Pe ife ni Olorun, E ki o ha gb' oro Re? K'e gba ileri Re gbo? W' Oluwa nyin l' odo nyin, Jesu n sun: w' omije Re Eje Re pelu n ke pe, "Ee se ti e o fi ku?" Source: Yoruba Baptist Hymnal #175 Sinners, turn: why will you die? God, your maker, asks you why. God, who did your being give, Gave