Ija D'opin, Ogun Si Tan
Author Unknown Translated from Latin to English by Francis Pott Alleluya! Alleluya!! Alleluya!!! Ija d' opin, ogun si tan: Olugbala jagun molu: Orin ayọ l' a o ma kọ. Alleluya! Gbogbo ipa n' iku si lo: Ṣugbọn Kristi f' ogun rẹ ka: Aye ẹ ho iho ayọ - Alleluya! Ọjọ mẹta na ti kọja. O jinde kuro nin' oku: Ẹ f' ogo fun Ọlọrun wa. -Alleluya! O d' ẹwọn ọrun apadi, O s' ilẹkun ọrun silẹ: E kọrin iyin 'ṣẹgun Re. - Alleluya! Jesu nipa iya t' O jẹ, A bọ lọwọ iku titi: Titi l' a o si ma yin Ọ. - Alleluya! Source: Yoruba Baptist Hymnal #123 Alleluia, alleluia, alleluia! The strife is o'er, the battle done, the victory of life is won; the song of triumph has begun. Alleluia! The powers of death have done their worst, but Christ their legions hath dispersed: let shout of holy joy outburst. Alleluia! The three sad days are quickly sped, he rises glorious from the dead: all glory to our risen Head! Alleluia! ...