Oro Ogbologbo / Ancient Words
Ronnie C. Jr. Freeman / Tony W. Wood Yoruba Translator: Ayobami Temitope Kehinde (08/19/2019) Oro mimo, ogbologbo Fun 'rin wa, laye yii, Won fokan Olorun han Je k'oro atijo nipa. Oro iye, ireti Fun wa ni agbara Ninu aye ti a wa yi Or' atijo mu wa dele. Egbe: Oro otito atijo O n yi wa pada, A si okan wa paya Je koro atijo nipa Oro mimo t'igbagbo wa Ta fi le wa lowo Nipase irubo Teti sor' otito Kristi Oro mimo, ogbologbo Fun 'rin wa, laye yii, Won f'okan Olorun han Je k'oro atijo nipa. Egbe Eje awon Mataya, Won ku fun igbagbo yii Gbohun won lodun dodun E moro yii lokukudun. Egbe Holy words long preserved For our walk in this world, They resound with God’s own heart. Oh let the ancient words impart. Words of Life, words of Hope Give us strength, help us cope In this world, where e’er we roam Ancient words will guide us Home. CHORUS: Ancient words ever true Changing me and changing you, We