Featured post

KRIST' KI 'JOBA RE DE

Words: Lewis Hensley, 1867 Music: St. Cecilia, Kingsland Krist' ki 'joba Re de, Ki ase Re bere; F' opa-rin Re fo Gbogbo...

Tuesday, 25 March 2014

ENI BA GBEKELE OLUWA

Ẹni ba gbẹkẹle Ọlọrun;
L'abo l'ọrun at'aye;
Ẹni ba f'ifẹ wo Jesu;
Ko s'ẹru ti n daamu rẹ.

L'ara rẹ nikan oluwa;
Ni mo r'adun itunu;
Asa f'ọta at'ogun mi;
Igbala mi t'o daju. 

Ninu ijakadi aye;
L'emi o duro ṣinsin;
'Danwo yoo sọ ipa rẹ nu;
Nitori 'wọ o ṣọ mi.

Oluwa s'ẹri ibukun rẹ;
S'ara ati ọkan mi;
Jẹ t'emi si ṣe m'ni tirẹ;
Nitori iku Jesu.

4 comments:

 1. i just came across your blog today via google whil looking for the 2nd stanza of eyin te fe oluwa...you brought back union baptist church ikoyi quaters ile-ife's memories....i love your blog!more power

  ReplyDelete
  Replies
  1. Thank you sis! I'm glad to know this blog met your need. I'm encouraged. <3 <3 , Much love!

   Delete
 2. My dear sis, a friend sang this hymn for me and i searched the internet for the lyrics, i should have come here first. I have been using your blog to get lyrics for some time and i found it here again today. Thank you sis and more grace to you. Please continue the Lord bless you.

  ReplyDelete