Posts

Showing posts with the label Evening hymn

Ogo F'Olorun Lale Yii

Text: Thomas Ken, 1637-1710 Music: Thomas Tallis, c. 1505-1585 Ogo f'Olorun l' ale yi Fun gbogbo ore imole, So mi, Oba awon oba Labe ojiji iye Re Oluwa, f' ese mi ji mi, Nitori Omo Re loni; K' emi le wa l' Alafia Pelu Iwo ati aiye. Ko mi ki nwa, kin le ma wo Iboji t'emi b' eni mi; Ko mi, ki nku, kin le dide Ninu ogo l' ojo 'dajo. Je k' okan mi le sun le O K' orun  didun p' oju mi de; Orun ti y'o m' ara mi le Ki nle sin O li owuro. Bi mo ba dubule laisun, F' ero orun kun okan mi Ma je ki nl' ala buburu Ma je k' ipa okun bo mi. Yin Oluwa, gbogbo eda Ti mbe n' isale aiye yi; E yin l' oke, eda orun, Yin Baba, Omo on Emi. Source: Yoruba Baptist Hymnal #71 Glory to thee, my God, this night, For all the blessings of the light: Keep me, O keep me, King of kings, Beneath thine own almighty wings Forgive me, Lord, for thy dear Son, the ill that I this day have