Ija D'opin, Ogun Si Tan
Author Unknown Translated from Latin to English by Francis Pott Alleluya! Alleluya!! Alleluya!!! Ija d' opin, ogun si tan: Olugbala jagun molu: Orin ayo l' a o ma ko. Alleluya! Gbogbo ipa n' iku si lo: Sugbon Kristi f' ogun re ka: Aiye E ho iho ayo - Alleluya! Ojo meta na ti koja. O jinde kuro nin' oku: E f' ogo fun Olorun wa. -Alleluya! O d' ewon orun apadi, O s' ilekun orun sile: E korin iyin 'segun Re. - Alleluya! Jesu nipa iya t' O je, A bo lowo iku titi: Titi l' a o si ma yin O. - Alleluya! Source: Yoruba Baptist Hymnal #123 Alleluia, alleluia, alleluia! The strife is o'er, the battle done, the victory of life is won; the song of triumph has begun. Alleluia! The powers of death have done their worst, but Christ their legions hath dispersed: let shout of holy joy outburst. Alleluia! The three sad days are quickly sped, he rises glorious from the dead: all glory to our risen Head! Allelui...