Ija D'opin, Ogun Si Tan

Author Unknown
Translated from Latin to English by Francis Pott
Alleluya! Alleluya!! Alleluya!!!
Ija d' opin, ogun si tan:
Olugbala jagun molu:
Orin ayọ l' a o ma kọ.
Alleluya!

Gbogbo ipa n' iku si lo:
Ṣugbọn Kristi f' ogun rẹ ka:
Aye ẹ ho iho ayọ - Alleluya!

Ọjọ mẹta na ti kọja.
O jinde kuro nin' oku:
Ẹ f' ogo fun Ọlọrun wa. -Alleluya!

O d' ẹwọn ọrun apadi,
O s' ilẹkun ọrun silẹ:
E kọrin iyin 'ṣẹgun Re. - Alleluya!

Jesu nipa iya t' O jẹ,
A bọ lọwọ iku titi:
Titi l' a o si ma yin Ọ. - Alleluya!

Source: Yoruba Baptist Hymnal #123
Alleluia, alleluia, alleluia!
The strife is o'er, the battle done,
the victory of life is won;
the song of triumph has begun.
 Alleluia!

The powers of death have done their worst,
but Christ their legions hath dispersed:
let shout of holy joy outburst.
Alleluia!

The three sad days are quickly sped,
he rises glorious from the dead:
all glory to our risen Head!
Alleluia!

 He closed the yawning gates of hell,
the bars from heaven's high portals fell;
let hymns of praise his triumphs tell!
Alleluia!

Lord! by the stripes which wounded thee,
from death's dread sting thy servants free,
that we may live and sing to thee.
Alleluia!
  Source:http://www.oremus.org/hymnal/t/t368.html

Comments

Popular posts from this blog

JESU NI BALOGUN OKO

E BA WA YIN OLUWA, ALLELUYA!

Mo N Tesiwaju Lona Na