Posts

Showing posts with the label Jesus' love

Mo Yo Pupo Pe Jesu Fe Mi

Author:  Philip P Bliss Mo yo pipo pe Baba wa orun So t'ife Re ninu 'we t'o fun mi, Mo r' ohun 'yanu ninu Bibeli, Eyi sowon ju pe Jesu fe mi, Egbe Mo yo pipo pe Jesu fe mi, Jesu fe mi, Jesu fe mi, Mo yo pipo pe Jesu fe mi, Jesu fe an' emi. Gba mo gbagbe Re, ti emi salo O fe mi sibe, O wa mi kiri, Mo yara pada s' apa anu Re, 'Gbati mo ranti pe Jesu fe mi. Bi o se orin kan l' emi le ko, 'Gba mo r' Oba nla ninu ewa Re, Eyi yio ma j'orin mi titii, A! iyanu nipe Jesu fe mi. Jesu fe mi mo si mo pe mo fe E, Ife l'o m' U wa r' okan mi pada, Ife lo m' U ko ku l' ori igi, O da mi loju pe Jesu fe mi. Emi o ti se dahun b' a bi mi Ohun ti Ogo Oluwa mi je? Emi Mimo njeri nin' okan mi, Ni igbagbo pe Jesu fe mi. Ni igbekele yi mo r' isimi, Ni 'gbekele Krist, mo d' alabukun, Satan damu sa kuro l' okan mi, Nigba mo so fun pe Jesu ...