Gbo Ohun Jesu Ti N Ke Pe

Author: Daniel March, 1868.

Gbo ohun Jesu ti n ke pe,
Tani yoo sise loni?
Oko pon pupo fun 'kore,
Tani yi o lo ka a?
Kikankikan l'Oluwa npe
Ebun nla lo fi fun o.
Tani yo fayo dahun pe,
"Emi ni'i ran mi, ran mi."

Biwo ko le la okun lo,
Lati wa 'won keferi,
O le ri won nitosi re,
Won wa lenu ona re;
Bo ko le fi wura tore,
O le fi baba tore,
Die to si se fun Jesu,
'Yebiye ni loju Re.

Bo ko le soro b'angeli,
Bo ko le wasu bi Paul'
Iwo le so tife Jesu,
O le so ti iku re;
Biwo ko le ji elese
Ninu ewu idajo,
'Wo le ko awon omode
Li ona t'Olugbala.

Biwo ko le kagbalagba,
Krist' Olusaguntan ni,
"Bo awon od'-aguntan Mi
Gbe ounje ti won lodo,"
O le je pe awon 'mode
To ti fi owo re to,
Ni yoo wa larin oso re
Gbat'o ba de'le rere.

Ma jek'eniyan gbo wipe,
"Ko si nkan temi le se,"
Nigba twon keferi nku,
Ti Oluwa si n pe o,
Fayo gba ise t'O pe o
Kise Re je ayo re;
Fayo dahun gbat'O pe o
Pe, "Emi ni yi, ran mi."
Source: Yoruba Baptist Hymnal #445
Hark, the voice of Jesus calling,
"Who will go and work today?
Fields are white and harvests waiting,
Who will bear the sheaves away?"
Loud and long the master calls you;
Rich reward he offers free.
Who will answer, gladly saying,
"Here am I. Send me, send me"?

If you cannot speak like angels,
If you cannot preach like Paul,
You can tell the love of Jesus;
You can say he died for all.
If you cannot rouse the wicked
With the judgment’s dread alarms,
You can lead the little children
To the Savior’s waiting arms.

If you cannot be a watchman,
Standing high on Zion’s wall,
Pointing out the path to heaven,
Offering life and peace to all,
With your prayers and with your bounties
You can do what God demands;
You can be life faithful Aaron,
Holding up the prophet’s hands.

Let none hear you idly saying,
"There is nothing I can do,"
While the multitudes are dying
And the master calls for you.
Take the task he gives you gladly;
Let his work your pleasure be.
Answer quickly when he calls you,
"Here am I. Send me, send me!"

Hymn # 318 from Lutheran Worship

This hymn was written while the author was a pastor in Philadelphia[Pennsylvania]. On the 18th of October he was to preach, by request, to the Christian Association of that city. At a late hour he learned that one of the hymns selected was not suitable. In great haste, he says, he wrote the hymn, and it was sung from the manuscript.

Nutter, p. 214

Comments

Popular posts from this blog

JESU NI BALOGUN OKO

Olori Ijo T'orun

E BA WA YIN OLUWA, ALLELUYA!