Olori Ijo T'orun
Words: Charles Wesley (1707-1788) Olori ijo torun Layo la wole fun O; K'O to de ijo t'aye Y'o ma korin bi torun A gbe okan wa soke Nireti to nibukun Awa kigbe, awa fiyin F'Olorun igbala wa. Bi a wa ninu 'ponju, T'a n koja ninu ina, Orin ife lawa o ko Ti yoo mu wa sun mo O Awa sape, a si yo Ninu ojurere Re Ife to so wa di tire Yoo pa wa mo titi lai. Iwo mu awon eeyan Re Koja isan idanwo A ki o beru wahala 'Tori O wa nitosi Aye, ese at'Esu, Koju ija si wa lasan Lagbara Re a o segun A o si korin Mose. Awa figbagbo rogo T'O n fe lati fi wa si A kegan ere aye Ti a fi siwaju wa Bi o ba si ka wa ye Awa pelu Stefen t'o ku Yoo ri O bo ti duro Lati pe wa lo sorun Head of Thy Church triumphant, We joyfully adore Thee; Till Thou appear, Thy members here Shall sing like those in glory. We lift our hearts and voices With blest anticipation, And cry aloud, and give to God The praise of our salvation. While in...