Okan Mi Yo Ninu Oluwa
Author: E.O. Excell Okan mi nyo ninu Oluwa ‘Tori O je iye fun mi Ohun Re dun pupo lati gbo Adun ni lati r’oju Re Emi yo ninu Re Emi yo ninu Re Gba 'gbogbo lo fayo kun okan mi ‘Tori emi nyo n’nu Re. O ti pe t’O ti nwa mi kiri ‘Gbati mo rin jina s’agbo O gbe mi wa sile l’apa Re Nibiti papa tutu wa Ire at’anu Re yi mi ka Or’ofe Re n san bi odo Emi Re nto, o si nse ‘tunu O n ba mi lo si ‘bikibi Emi y’o dabi Re ni ‘jo kan N o s’eru wuwo mi kale Titi di ‘gbana n o s’oloto Ni sise oso f’ade Re. Amin. Translated by Ayobami Temitope Kehinde Dec 15, 2018. My soul is so happy in Jesus, For He is so precious to me; His voice it is music to hear it, His face it is heaven to see. Refrain: I am happy in Him, I am happy in Him; My soul with delight He fills day and night, For I am happy in Him. He sought me so long ere I knew Him, When wand’ring afar from the fold; Safe home in His arms He hath bro't me, To where there...