Okan Mi Yin Oba Orun / Praise My Soul the King of Heaven
Words by Henry Francis Lyte Okan mi yin Oba orun Mu ore wa si odo Re; 'Wo ta wosan ta dariji, Ta la ba ha yin bi Re? Yin Oluwa/2x Yin Oba ainipekun. Yin, fun anu t'O ti fihan, Fawon Baba n'nu 'ponju; Yin I, okan na Ni titi, O lora lati binu, Yin Oluwa/2x Ologo n'nu otito. Bi baba ni O ntoju wa, O si mo ailera wa; Jeje l' O ngbe wa l' apa Re, O gba wa lowo ota, Yin Oluwa/2x Anu Re yi aiye ka. A ngba b' itanna eweko, T' afefe nfe, t' o si nro 'Gbati a nwa, ti a si nku, Olorun wa bakanna; Yin Oluwa/2x Oba alainipekun. Angel', e jumo ba wa bo, Enyin nri lojukoju; Orun, osupa, e wole, Ati gbogbo agbaiye, E ba wa yin/2x Olorun Olotito. Source: Yoruba Baptist Hymnal #301 Praise, my soul, the King of heaven; To his feet thy tribute bring. Ransomed, healed, restored, forgiven, Who are me his praise should sing? Alleluia, alleluia! Praise the everlasting King! Praise him for his grace and favour To...