Nigba Igbi Aye Ba Dide Si O / Ro 'Bukun Re / Count Your Blessings
Author: Johnson Oatman Jr (1856-1952) Nigba igbi aiye ba dide si o, T' okan re baje pe gbogbo nkan segbe, Siro ibukun re, ka won lokokan, Enu y'o ya o fun nkan t' Oluwa t'se. Refrain Ro 'bukun re ka won lokokan, Ro ohun t' Olorun se fun o; Ro 'bukun re, ka won lokokan, Ro 'bukun re, ri nkan t' Olorun ti se. Eru aniyan ha ti n pa okan re? Agbelebu ti 'wo nru ha si wuwo? Siro ibukun re le 'yemeji lo, Iwo y'o si korin b' ojo ti nkoja. Nigbat' ini elomi kun o loju, Ranti Krist n 'oro aimoye fun o, Siro ibukun re t' owo ko le ra, At' ere re lorun, ile re l' oke Beni larin ija b' o ti wu ko ri, Mase ba okan je mo p' Olorun mbe, Siro ibukun re, Angeli y'o wa, Fun ranwo on 'tunu d'opin ajo re. Source: YBH #658 When upon life’s billows you are tempest tossed, When you are discouraged, thinking all is lost, Count your many blessings name them one by one, And it will surp...