Halleluyah! Ogo Ni Fun Baba / Hallelujah! Glory To The Father
Author Unknown Translated to English by Ayobami Temitope Kehinde Ẹ jẹ ka jumọ f'ọpẹ f'Ọlorun Orin iyin, at'ọpẹ lo yẹ wa Iyanu n'ifẹ Rẹ si gbogbo wa Ẹ kọrin 'yin s' Ọba Olore wa Chorus: Halleluyah! Ogo ni fun Baba A f'ijo ilu yin Ọlọrun wa Alaye ni o yin Ọ bo ti yẹ Halleluyah! Ogo ni fun Baba Ki l'a fi san j'awọn t'iku ti pa? Iwọ lo f'ọwọ wọ wa di oni 'Wọ lo n sọ wa to n gba wa lọw'ewu Ẹ kọrin 'yin s'Olutọju wa Ohun wa ko dun to lati kọrin Ẹnu wa ko gboro to fun ọpẹ B'awa n'ẹgbẹrun ahọn nikọkan Wọn kere ju lati gb'ọla Rẹ ga Let us give thanks to God together Songs of praises and thanks are befitting Marvelous is Your love to all of us Oh sing praises to our Gracious King Chorus: Hallelujah! Glory to the Father We praise ou...