Jesu, Ise Re L'o/Thy Works, Not Mine, O Christ
Author: George R. Prynne JESU, ise Re l'o Fi ayo s'okan mi, Nwon ni, o ti pari, Ki eru mi ko tan: Odo tani emi 'ba lo, Lehin Iwo t'O s'etutu? Jesu, ogbe Re l'o Le m'okan mi jina; N'nu 'ya Re ni mo ri Iwosan f'ese mi: Odo tani emi 'ba lo, Lehin Iwo t'O s'etutu? Agbelebu Tire L'o gbe eru ese, T'enikan ko le gbe, Lehin Om'Olorun: Odo tani emi 'ba lo, Lehin Iwo t'O s'etutu? Ki se iku t'emi L'o san irapada; Egbarun bi t'emi Ko to, o kere ju; Odo tani emi 'ba lo, Lehin Iwo t'O s'etutu? Source: YBH 238 Thy works, not mine, O Christ, Speak gladness to this heart; They tell me all is done; They bid my fear depart. To whom, save Thee, who canst alone For sin atone, Lord, shall I flee? Thy pains, not mine, O Christ, Upon the shameful tree, Have paid the law’s full price And purchased peace for me. To whom, save Thee, who canst alone For sin atone, Lord, shall I flee? Thy cross, not mine, O Christ,...