Igbagbo Awọn Baba Wa/Faith of Our Fathers
1. Igbagbo awọn baba wa Ko bèru ida ati'na, Awa ọmọ wọn si l'ayo 'Gba t'a gbo 'royin 'gbagbo wọn! Igbagbo mimọ ti baba! A o j'olooto si ọ d'opin. 2. Igbagbo awọn baba wa, A o jere gbogb’aye fun ọ, Pelu otito Olorun, Awọn eeyan yoo d'om'nira: Igbagbo mimọ ti baba! A o j'olooto si o d'opin. 3. Igbagbo awọn baba wa, A o fèrán orè at'ota, Ao si f'ifè nla rohin rè Ninu oro at'iṣe wa; Igbagbo mimo ti baba! A o j'olooto si ọ d'opin. Source: DLCM GHS#78 Faith of our fathers, living still In spite of dungeon, fire and sword, O how our hearts beat high with joy Whene’er we hear that glorious word! Faith of our fathers! holy faith! We will be true to thee till death! Our fathers, chained in prisons dark, Were still in heart and conscience free; And blest would be their children’s fate, If they, like them should die for thee: Faith of our fathers! holy faith! We will be true to thee till death! Faith of our fathers, we will...