Words: Robert Grant E wole f'Oba, Ologo julo E korin ipaati ife Re Alabo wa ni, at'Eni Igbani O n gbenu ogo, Eleru ni iyin E so tipa Re, e so t'ore Re 'Mole laso Re, gobi Re orun B'ara ti n san ni keke ibinu Re Ipa ona ni a ko si le mo Aye yii pelu ekun re gbogbo Olorun, agbara Re lo da won O fi idi re mule, ko si le yi O si f'okun se oja igbaya re Itoju Re wa lara gbogbo won Ninu afefe, ninu imole Itoju Re wa nin'odo ti o n san O si wa ninu iri ati ojo Awa erupe, aw'alailera 'Wo la gbekele, O ki o da ni Anu Re ronu, o si le de opin Eleda, Alabo, Olugbala wa. 'Wo Alagbara, Onife julo B'awon angeli, ti nyin O loke Be lawa eda Re, niwon ta le se A o ma juba Re, a o ma yin O Oh, worship the King, all-glorious above, Oh, gratefully sing His pow’r and His love; Our Shield and Defender, the Ancient of Days, Pavilioned in splendor, and girded with praise. Oh, tell of His might, oh, sing of His grace, Whose r...