Okan Mi Yin Oba Orun / Praise My Soul the King of Heaven
 Words by Henry Francis Lyte      Okan mi yin Oba orun  Mu ore wa si odo Re;  'Wo ta wosan ta dariji,  Ta la ba ha yin bi Re?  Yin Oluwa/2x  Yin Oba ainipekun.   Yin, fun anu t'O ti fihan,  Fawon Baba n'nu 'ponju;  Yin I, okan na Ni titi,  O lora lati binu,  Yin Oluwa/2x  Ologo n'nu otito.   Bi baba ni O ntoju wa,  O si mo ailera wa;  Jeje l' O ngbe wa l' apa Re,  O gba wa lowo ota,  Yin Oluwa/2x  Anu Re yi aiye ka.   A ngba b' itanna eweko,  T' afefe nfe, t' o si nro  'Gbati a nwa, ti a si nku,  Olorun wa bakanna;  Yin Oluwa/2x  Oba alainipekun.   Angel', e jumo ba wa bo,  Enyin nri lojukoju;  Orun,  osupa, e wole,  Ati gbogbo agbaiye,  E ba wa yin/2x  Olorun Olotito.   Source: Yoruba Baptist Hymnal #301  Praise, my soul, the King of heaven;  To his feet thy tribute bring.  Ransomed, healed, restored, forgiven,  Who are me his praise should sing?  Alleluia, alleluia!  Praise the everlasting King!   Praise him for his grace and favour  To...