Posts

Wo Bo Ti Dun To Lati Ri

Wo! b' o ti dun to lati ri Awon ara t' o re; Ara ti okan won s' okan, L' egbe ide mimo. 'Gba isan 'fe t' odo Krist' sun, O san s' okan gbogbo; 'Lafia Olodumare Dabo bo gbogbo re. O dabi ororo didun, Ni irugbon Aaron'; Kikan re m' aso re run ' re O san s' agbada re. O dara b' iri owuro T' o nse s' oke Sion', Nibit' Olorun f' ogo han, T' O m' ore-ofe han. Behold, how good a thing it is, and how becoming well, Together such as brethren are in unity to dwell! Like precious ointment on the head, that down the beard did flow, Ev’n Aaron’s beard, and to the skirts, did of his garments go. As Hermon’s dew, the dew that doth on Sion’ hills descend: For there the blessing God commands, life that shall never end. Scottish Psalter and Paraphrases, 1650

Yin Oluwa, Oro Didun

Yin Oluwa, oro didun Yin oru 'dake je, Gbogbo aiye so ogo Re, Yin, irawo 'mole. Yin, enyin iji t' o dide N' igboran s' ase Re K' oke at' igi eleso Dapo yin Oluwa. E fi ete nyin mimo yin Enyin ogun orun; Ogo, ola at' agbara Fun Oba 'yeraiye. Eyin, enyin mimo ti nyo Nihin. Nin 'ase Re Orun adura eniti Nt' ori pepe g' oke E yin gbogbo ise Re ti O wa n' ikawo Re, Oluwa, ola Re ti to! Okan mi yin l' ogo. Praise ye the Lord on the glad morning, Praise ye the silent night. All the earth speak of all Thy great glory, Praise Him star and light. Praise Him all the rising great storm, In obedience to His will, Let all the mountains and all the forest, All join to praise Him. All praise Him with your holy tongue, Praise Him all angels above, Glory, power, might and adoration, To the mighty God. Praise Him, praise Him all the holy tongue, Here in His sanctuary. The sweet smell of your supplications,...

E Tun Won Ko Fun Mi Ki N Gbo (Wonderful Words Of Life)

Author: P. P. Bliss E tun won ko fun mi ki ngbo Oro 'yanu t' Iye! Je ki nsi tun ewa won ri, Oro 'yanu t' Iye, Oro iye at' ewa, ti mko mi n' igbagbo! Refrain: Oro didun! Oro 'yanu Oro didun! Oro 'yanu Oro 'yanu t' Iye. Oro 'yanu t' Iye. Kristi nikan lo fi fun ni Oro 'yanu t' Iye! Elese gbo 'pe ife na Oro 'yanu t' Iye, L' ofe la fifun wa, ko le to wa s'orun Gbo ohun ihinrere na, Oro 'yanu t' Iye! F' igbala lo gbogbo enia Oro 'yanu t' Iye, Jesu Olugbala, we wa mo titi lai! Source: Yoruba Baptist Hymnal # 615 Sing them over again to me, Wonderful words of life; Let me more of their beauty see, Wonderful words of life; Words of life and beauty, Teach me faith and duty: Refrain: Beautiful words, wonderful words, Wonderful words of life; Beautiful words, wonderful words, wonderful words of life. Christ, the blessed One, gives to all Wonderful words of lif...

Yin Oluwa, Orun Wole

Author: Franz Joseph Hadyn Yin Oluwa, orun wole Yin enyin mimo l' oke K' orun at' osupa ko, K' awon 'rawo f' iyin fun. Yin Oluwa, O ti s' oro, Awon aiye gb' ohun Re, Fun nwon O fi ofin le'le, T' a ko le baje titi. Yin, nitoriti O l' ola, Ileri Re ko le yi; O ti mu awon enia Re Bori iku on ese. Yin Olorun igbala wa, Ogun orun, so pa Re, Orun, aiye, gbogbo eda, Yin, k' e gb' oruko Re ga. Praise the Lord! O heavens adore him, Praise him, angels in the height; Sun and moon, bow down before him; Praise him, shining stars of light. Praise the Lord, for he hath spoken; Worlds his mighty voice obeyed; Laws which never shall be broken for their guidance he has made. Praise the Lord, for he is gracious; Never shall his promise fail. God has made his saints victorious; Sin and death shall not prevail. Praise the God of our salvation; Hosts on high, his power proclaim; Heaven and earth, and all creation...

Ileri Mimo, Jesu N'temi

Words: Fanny Jane Crosby Ileri mimo, Jesu n'temi; Adun ogo nla, orun didan; Ajogun igbala, omo Olorun; Omo Emi ta fi eje we. Refrain: Eyi nitan mi, atorin mi Ki n ma yin Jesu lojo gbogbo, Eyi nitan mi, atorin mi- Ki n ma yin Jesu lojo gbogbo. Ijewo mimo, ayo didun Iran ayo nla 'be niwaju mi Angel' sokale lati orun Pelu iyin, ayo at'ife Ijewo mimo, mo r'isinmi Ninu Oluwa, mo r'ibukun Mo duro, mo n sona mo n woke Mo kun fun ore at'ife Re Blessed assurance, Jesus is mine; Oh, what a foretaste of glory divine! Heir of salvation, purchase of God, Born of His Spirit, washed in His blood. Refrain: This is my story, this is my song, Praising my Savior all the day long. This is my story, this is my song, Praising my Savior all the day long. Perfect submission, perfect delight, Visions of rapture now burst on my sight; Angels descending, bring from above Echoes of mercy, whispers of love. Perfect submission, all is at res...

Okan Mi Yin Oba Orun / Praise My Soul the King of Heaven

Words by Henry Francis Lyte Okan mi yin Oba orun Mu ore wa si odo Re; 'Wo ta wosan ta dariji, Ta la ba ha yin bi Re? Yin Oluwa/2x Yin Oba ainipekun. Yin, fun anu t'O ti fihan, Fawon Baba n'nu 'ponju; Yin I, okan na Ni titi, O lora lati binu, Yin Oluwa/2x Ologo n'nu otito. Bi baba ni O ntoju wa, O si mo ailera wa; Jeje l' O ngbe wa l' apa Re, O gba wa lowo ota, Yin Oluwa/2x Anu Re yi aiye ka. A ngba b' itanna eweko, T' afefe nfe, t' o si nro 'Gbati a nwa, ti a si nku, Olorun wa bakanna; Yin Oluwa/2x Oba alainipekun. Angel', e jumo ba wa bo, Enyin nri lojukoju; Orun, osupa, e wole, Ati gbogbo agbaiye, E ba wa yin/2x Olorun Olotito. Source: Yoruba Baptist Hymnal #301 Praise, my soul, the King of heaven; To his feet thy tribute bring. Ransomed, healed, restored, forgiven, Who are me his praise should sing? Alleluia, alleluia! Praise the everlasting King! Praise him for his grace and favour To...

A! Mba Le L'egberun Ahon

Author: Charles Wesley A! mba le l' egberun ahon. Fun 'yin Olugbala, Ogo Olorun Oba mi, Isegun ore Re. Jesu t' O s' eru wa d' ayo, T' O mu 'banuje tan; Orin ni l' eti elese, Iye at' ilera. O segun agbara ese O da ara tubu; Eje Re le w' eleri mo, Eje Re seun fun mi O soro oku gbohun Re O gba emi titun Onirobinuje y'ayo Otosi si gbagbo Odi, e korin iyin Re Aditi gbohun Re Afoju, Olugbala de Ayaro fo f'ayo Baba mi at' Olorun mi, Fun mi n' iranwo Re; Ki nle ro ka gbogbo aiye, Ola oruko Re. Source: Yoruba Baptist Hymnal #291 &  Iwe Orin Irapada Ti Ijo Aposteli Na #8 O for a thousand tongues to sing My dear Redeemer's praise! The glories of my God and King, The triumphs of His grace! Jesus! the Name that charms our fears, That bids our sorrows cease; 'Tis music in the sinner's ears, 'Tis life, and health, and peace. He breaks the power of cancell'd sin, He set...