Posts

Nigba Igbi Aye Ba Dide Si O / Ro 'Bukun Re / Count Your Blessings

Author: Johnson Oatman Jr (1856-1952) Nigba igbi aiye ba dide si o, T' okan re baje pe gbogbo nkan segbe, Siro ibukun re, ka won lokokan, Enu y'o ya o fun nkan t' Oluwa t'se. Refrain Ro 'bukun re ka won lokokan, Ro ohun t' Olorun se fun o; Ro 'bukun re, ka won lokokan, Ro 'bukun re, ri nkan t' Olorun ti se. Eru aniyan ha ti n pa okan re? Agbelebu ti 'wo nru ha si wuwo? Siro ibukun re le 'yemeji lo, Iwo y'o si korin b' ojo ti nkoja. Nigbat' ini elomi kun o loju, Ranti Krist n 'oro aimoye fun o, Siro ibukun re t' owo ko le ra, At' ere re lorun, ile re l' oke Beni larin ija b' o ti wu ko ri, Mase ba okan je mo p' Olorun mbe, Siro ibukun re, Angeli y'o wa, Fun ranwo on 'tunu d'opin ajo re. Source: YBH #658 When upon life’s billows you are tempest tossed, When you are discouraged, thinking all is lost, Count your many blessings name them one by one, And it will surp...

Olorun Awa Fe / We Love The Place, O God

Olorun awa fe, Ile t' ola Re wa; Ayo ibugbe Re Ju gbogbo ayo lo. Ile adura ni, Fun awon omo Re Jesu si wa nibe, Lati gbo ebe won. Awa fe ase Re, Ti nte okan l' orun Iwo l' onje iye, Ti onigbagbo nje. Awa fe oro Re, Oro alafia T' itunu at 'iye Oro ayo titi. Awa fe orin Re, Ti a nko l' aiye yi; Sugbon awa fe mo, Orin ayo t' orun. Jesu Oluwa wa, Busi 'fe wa nihin; Mu wa de 'nu ogo, Lati yin O titi. Source: Yoruba Baptist Hymnal #42 We love the place, O God, in which your honour dwells: the joy of your abode, all earthly joy excels. We love the house of prayer: for where Christ's people meet, our risen Lord is there to make our joy complete. We love the word of life, the word that tells of peace, of comfort in the strife and joys that never cease. We love the cleansing sign of life through Christ our Lord, where with the name divine we seal the child of God. We love the holy feast where, nourishe...

Wo Bo Ti Dun To Lati Ri

Wo! b' o ti dun to lati ri Awon ara t' o re; Ara ti okan won s' okan, L' egbe ide mimo. 'Gba isan 'fe t' odo Krist' sun, O san s' okan gbogbo; 'Lafia Olodumare Dabo bo gbogbo re. O dabi ororo didun, Ni irugbon Aaron'; Kikan re m' aso re run ' re O san s' agbada re. O dara b' iri owuro T' o nse s' oke Sion', Nibit' Olorun f' ogo han, T' O m' ore-ofe han. Behold, how good a thing it is, and how becoming well, Together such as brethren are in unity to dwell! Like precious ointment on the head, that down the beard did flow, Ev’n Aaron’s beard, and to the skirts, did of his garments go. As Hermon’s dew, the dew that doth on Sion’ hills descend: For there the blessing God commands, life that shall never end. Scottish Psalter and Paraphrases, 1650

Yin Oluwa, Oro Didun

Yin Oluwa, oro didun Yin oru 'dake je, Gbogbo aiye so ogo Re, Yin, irawo 'mole. Yin, enyin iji t' o dide N' igboran s' ase Re K' oke at' igi eleso Dapo yin Oluwa. E fi ete nyin mimo yin Enyin ogun orun; Ogo, ola at' agbara Fun Oba 'yeraiye. Eyin, enyin mimo ti nyo Nihin. Nin 'ase Re Orun adura eniti Nt' ori pepe g' oke E yin gbogbo ise Re ti O wa n' ikawo Re, Oluwa, ola Re ti to! Okan mi yin l' ogo. Praise ye the Lord on the glad morning, Praise ye the silent night. All the earth speak of all Thy great glory, Praise Him star and light. Praise Him all the rising great storm, In obedience to His will, Let all the mountains and all the forest, All join to praise Him. All praise Him with your holy tongue, Praise Him all angels above, Glory, power, might and adoration, To the mighty God. Praise Him, praise Him all the holy tongue, Here in His sanctuary. The sweet smell of your supplications,...

E Tun Won Ko Fun Mi Ki N Gbo (Wonderful Words Of Life)

Author: P. P. Bliss E tun won ko fun mi ki ngbo Oro 'yanu t' Iye! Je ki nsi tun ewa won ri, Oro 'yanu t' Iye, Oro iye at' ewa, ti mko mi n' igbagbo! Refrain: Oro didun! Oro 'yanu Oro didun! Oro 'yanu Oro 'yanu t' Iye. Oro 'yanu t' Iye. Kristi nikan lo fi fun ni Oro 'yanu t' Iye! Elese gbo 'pe ife na Oro 'yanu t' Iye, L' ofe la fifun wa, ko le to wa s'orun Gbo ohun ihinrere na, Oro 'yanu t' Iye! F' igbala lo gbogbo enia Oro 'yanu t' Iye, Jesu Olugbala, we wa mo titi lai! Source: Yoruba Baptist Hymnal # 615 Sing them over again to me, Wonderful words of life; Let me more of their beauty see, Wonderful words of life; Words of life and beauty, Teach me faith and duty: Refrain: Beautiful words, wonderful words, Wonderful words of life; Beautiful words, wonderful words, wonderful words of life. Christ, the blessed One, gives to all Wonderful words of lif...

Yin Oluwa, Orun Wole

Author: Franz Joseph Hadyn Yin Oluwa, orun wole Yin enyin mimo l' oke K' orun at' osupa ko, K' awon 'rawo f' iyin fun. Yin Oluwa, O ti s' oro, Awon aiye gb' ohun Re, Fun nwon O fi ofin le'le, T' a ko le baje titi. Yin, nitoriti O l' ola, Ileri Re ko le yi; O ti mu awon enia Re Bori iku on ese. Yin Olorun igbala wa, Ogun orun, so pa Re, Orun, aiye, gbogbo eda, Yin, k' e gb' oruko Re ga. Praise the Lord! O heavens adore him, Praise him, angels in the height; Sun and moon, bow down before him; Praise him, shining stars of light. Praise the Lord, for he hath spoken; Worlds his mighty voice obeyed; Laws which never shall be broken for their guidance he has made. Praise the Lord, for he is gracious; Never shall his promise fail. God has made his saints victorious; Sin and death shall not prevail. Praise the God of our salvation; Hosts on high, his power proclaim; Heaven and earth, and all creation...

Ileri Mimo, Jesu N'temi

Words: Fanny Jane Crosby Ileri mimo, Jesu n'temi; Adun ogo nla, orun didan; Ajogun igbala, omo Olorun; Omo Emi ta fi eje we. Refrain: Eyi nitan mi, atorin mi Ki n ma yin Jesu lojo gbogbo, Eyi nitan mi, atorin mi- Ki n ma yin Jesu lojo gbogbo. Ijewo mimo, ayo didun Iran ayo nla 'be niwaju mi Angel' sokale lati orun Pelu iyin, ayo at'ife Ijewo mimo, mo r'isinmi Ninu Oluwa, mo r'ibukun Mo duro, mo n sona mo n woke Mo kun fun ore at'ife Re Blessed assurance, Jesus is mine; Oh, what a foretaste of glory divine! Heir of salvation, purchase of God, Born of His Spirit, washed in His blood. Refrain: This is my story, this is my song, Praising my Savior all the day long. This is my story, this is my song, Praising my Savior all the day long. Perfect submission, perfect delight, Visions of rapture now burst on my sight; Angels descending, bring from above Echoes of mercy, whispers of love. Perfect submission, all is at res...