Jesu N Pe WA L'osan l'oru
  Author: Cecil Frances Alexander (1852)      Jesu npe wa l' osan, l' oru  Larin irumi aiye;  Lojojumo l' a ngb' ohun Re  Wipe, "Kristian, tele Mi."   Awon Apostili 'gbani,  Ni odo Galili ni;  Nwon ko ile, ona sile,  Gbogbo nwon si nto lehin.   Jesu npe wa larin lala  Aiye wa buburu yi;  Larin Afe aiye, O nwi  Pe, "Kristian, e feran Mi."   Larin ayo at' ekun wa,  Larin 'rora on osi,  Tantan L' O npe l' ohun rara  Pe, "Kristian, e feran Mi."   Olugbala, nip' anu Re,  Je ki a gbo ipe Re,  F' eti 'gboran fun gbogbo wa,  K' a fe O ju aiye lo.   Jesus calls us: o'er the tumult  Of our life's wild, restless sea;  Day by day his sweet voice soundeth  Saying, "Christian, follow me."   As, of old, apostles heard it  By the Galilean lake,  Turned from home and toil and kindred,  Leaving all for his dear sake.  Jesus calls us from the worship  Of the vain world's golden store,  From each idol t...