Posts

Ko Je Gbagbe Mi

Author: Evangelist D.O Babajide Ore bi Jesu ko si laye yi Oun nikan l'ore otito Ore aye yi le ko wa sile Sugbon Jesu ko je gbagbe wa Ah! Ko je gbagbe wa/ 2ce Sugbon Jesu ko je gbagbe wa Akoko nkoja lo laifotape A f ojo kan sunmole wa si Onidajo mbo gongo yio so Awawi kan kosi l ojo na Duro d'Oluwa, ma siyemeji Ohunkohun t' o wu ko le de Gbat o ro p'o pin ranwo Re y'o de Eni yanu l oba Oluwa There is no friend like Jesus in the world Jesus is the only sincere friend The friend of this world will one day leave us But the Lord will never forget us He'll never forget us/2ce But the Lord will never forget us Not caring for foes, the time is passing Drawing near to our home day by day The Great Judge will come  the earth will tremble There will be no excuse on the day Now, wait on the Lord, never doubt again Whatever now may betide thee When there's no more hope, then His help will come Our Lord Jesus is a wonderful King  ...

A nsoro ile bukun ni

Writer:  Elizabeth K. Mills A nsoro ile bukun ni Ile didan atile ewa N'gba gbogbo la nso togo re Yo ti dun to lati de 'be! A nsoro ita wura re Oso odi re ti ko legbe Faji re ko se fenu so Yo ti dun to lati de 'be! A n so pese ko si nibe Ko saniyan at'ibanuje Pelu 'danwo lode ninu Yo ti dun to lati de 'be A soro orin iyin re Ti a ko le forin aye we, Bo ti wu korin wa dun to Yo ti dun to lati de 'be! A n soro isin ife re Ti agbada tawon mimo nwo Ijo akobi ti oke Yo ti dun to lati de 'be! Jo Oluwa tibi tire Sa se emi wa ye fun orun Laipe awa na yio mo Bo ti dun to lati de 'be Source: Yoruba Baptist Hymnal #535 We speak of the realms of the Blest, Of that country so bright and so fair, And oft are its glories confessed; But what must it be to be there? We speak of its pathways of gold, Of its walls decked with jewels most rare, Its wonders and pleasures untold; But what must it be to be there? We speak of its ...

Baba, Mo N'owo Mi Si O

Writer: Charles Wesley Baba, mo n' owo mi si O; Nko mo 'ranwo miran: Bi O ba kuro lodo mi, A! nibo ni ngo lo? Ohun t' OmoRe f' ara da Ki nto la 'ju s' aiye! Ise t' O se lati gba mi Lowo 'ku ailopin! Orisun 'gbagbo, si O ni Mo gb' oju are mi: Mba je le ri ebun ni gba Laisi re mo segbe. Source: Yoruba Baptist Hymnal #220 Father, I stretch my hands to Thee, No other help I know; If Thou withdraw Thyself from me, Ah! Whither shall I go? On Thy dear Son I now believe O let me feel Thy power And all my varied wants relieve In this accepted hour Author of faith! to Thee I lift My weary longing eyes O let me now receive this gift My soul without it dies Surely Thou canst not let me die; O speak, and I shall live; And here I will unwearied lie, Till Thou Thy Spirit give. How would my fainting soul rejoice Could I but see Thy face Now let me hear Thy quickening voice And taste Thy pardoning grace I do b...

Ojo 'Dajo, Ojo Eru

Author: John Newton (1774) Ojo 'dajo, ojo eru! Gbo bi ipe tin dun to! O ju egbarun ara lo, O sin mi gbogbo aiye. Bi esun na Yio ti damu elese. Wo Onidajo l' awo wa, O woo go nla l' aso, Gbogbo wa ti now ona Re, Gbana ni nwon o ma yo. Olugbala, Jewo mi ni ijo na. Ni pipe Re, oku yio ji Lat' okun, ile, s' iye Gbogbo ipa aiye yio mi, Nwon o salo l' oju Re, Alaironu, Yio ha ti ri fun O? Sugbon f'a won t' o jewo Re, T' nwon fe, tin won sin l' aiye, Yio pe, "Wa, alabukunfun; Wo ' joba ti Mo fun nyin, Titi aiye, L'e o mo 'fe at' ogo Mi." Source: Baptist Hymnal #521 Day of judgment! Day of wonders! Hark! the trumpet’s awful sound, Louder than a thousand thunders, Shakes the vast creation round! How the summons wilt the sinner’s heart confound! See the Judge, our nature wearing, Clothed in majesty divine! You who long for His appearing Then shall say, “Th...

E BA WA YIN OLUWA, ALLELUYA!

Image
Eni t'O f'orun sile t'O wa s'aye Lati ku fun ese araye gbogbo; E korin aleluya s'Oba mimo Eni ba more Jesu ko ba wa gbe ga. Refrain: E ba wa yin Oluwa,  Aleluya! Eni ba more Jesu ko ba wa gbe ga, E ba wa yin Oluwa,  Aleluya! Eni ba more Jesu ko ba wa gbe ga, Eni ba more Jesu ko ba wa gbe ga. E ba wa yin Oluwa,  Aleluya! Eni ba more Jesu ko ba wa gbe ga. Eni t'O pa wa mo o lojojumo, Eni t'O n yo wa ninu ewu gbogbo Eni t'O n pa Israeli mo k'itogbe Eni ba more Jesu ko ba wa gbe ga. Eni t'O n pese fun aini wa laye, Eni t'O n sore fun wa lojo gbogbo, Ore t'O n se fun wa ko l'onka rara; Eni ba more Jesu ko ba wa gbe ga. He who left heav'n and came into the world And to die for the sins of all the people Sing hallelujah unto the holy King He who knows the goodness of Jesus should praise Him. Refrain: Come and let us praise the Lord, Hallelujah! He who knows the goodness of Jesus should praise Him...

Jesu O Seun/ Jesus Thank You

Writer:Pat Sczebel Adiitu agbelebu ko ye mi sibẹ, Irora ti Kalfari-- Ìwọ t'O pe t'O si mọ lu Ọmọ Rẹ T'O m'ago ikoro to yẹ ki n mu. Chorus Ẹ̀jẹ̀ Rẹ ti wẹṣẹ mi nu, Jesu O seun. Irunu Ọlọrun walẹ pata, Jesu O seun. Mo ti jọta Rẹ ri, Wayi mo n ba Ọ jeun, Jesu O seun. Nipa 'rubọ pipe Rẹ la fi fa mi, O s' ọta Rẹ dọrẹ Rẹ; Ọrọ or'ọfẹ ologo Rẹ lo tu jade, Aanu at' inu're Rẹ ko lopin. Bridge Olufẹ́ ọkan mi, Mo fẹ́ ma wa fun Ọ. Translated by Ayobami Temitope  Kehinde (21/04/2017) The mystery of the cross I cannot comprehend The agonies of Calvary-- You the perfect Holy One, crushed Your Son, Who drank the bitter cup reserved for me. CHORUS Your blood has washed away my sin Jesus, thank You The Father’s wrath completely satisfied Jesus, thank You Once Your enemy, now seated at Your table Jesus, thank You By Your perfect sacrifice I’ve been brought near, Your enemy You’ve made Your friend; Pouring out the riches of Yo...

Lojoojo, Oluwa/ Day By Day, Dear Lord

Image
Author:Richard of Chichester (1197 – 3 April 1253) Lojoojo, Oluwa Ohun meta mo beere K'emi le ri O sii Ki n le nife Re sii K'emi le tele O sii Lojoojo Translation by Ayobami Temitope (19/04/2017) Day by day, dear Lord of you Three things I pray: To see you more clearly, To love you more dearly, To follow you more nearly, Day by day. Source here