Posts

Olori Ijo T'orun

Image
Words: Charles Wesley (1707-1788) Olori ijo torun Layo la wole fun O; K'O to de ijo t'aye Y'o ma korin bi torun A gbe okan wa soke Nireti to nibukun Awa kigbe, awa fiyin F'Olorun igbala wa. Bi a wa ninu 'ponju, T'a n koja ninu ina, Orin ife lawa o ko Ti yoo mu wa sun mo O Awa sape, a si yo Ninu ojurere Re Ife to so wa di tire Yoo pa wa mo titi lai. Iwo mu awon eeyan Re Koja isan idanwo A ki o beru wahala 'Tori O wa nitosi Aye, ese at'Esu, Koju ija si wa lasan Lagbara Re a o segun A o si korin Mose. Awa figbagbo rogo T'O n fe lati fi wa si A kegan ere aye Ti a fi siwaju wa Bi o ba si ka wa ye Awa pelu Stefen t'o ku Yoo ri O bo ti duro Lati pe wa lo sorun Head of Thy Church triumphant, We joyfully adore Thee; Till Thou appear, Thy members here Shall sing like those in glory. We lift our hearts and voices With blest anticipation, And cry aloud, and give to God The praise of our salvation. While in

JESU N PE WA

Image
Author: Cecil Frances Alexander (1852) Jesu npe wa l' osan, l' oru Larin irumi aiye; Lojojumo l' a ngb' ohun Re Wipe, "Kristian, tele Mi." Awon Apostili 'gbani, Ni odo Galili ni; Nwon ko ile, ona sile, Gbogbo nwon si nto lehin. Jesu npe wa larin lala Aiye wa buburu yi; Larin Afe aiye, O nwi Pe, "Kristian, e feran Mi." Larin ayo at' ekun wa, Larin 'rora on osi, Tantan L' O npe l' ohun rara Pe, "Kristian, e feran Mi." Olugbala, nip' anu Re, Je ki a gbo ipe Re, F' eti 'gboran fun gbogbo wa, K' a fe O ju aiye lo. Jesus calls us: o'er the tumult Of our life's wild, restless sea; Day by day his sweet voice soundeth Saying, "Christian, follow me." As, of old, apostles heard it By the Galilean lake, Turned from home and toil and kindred, Leaving all for his dear sake. Jesus calls us from the worship Of the vain world's golden store, From each idol t

E WOLE FOBA

Words: Robert Grant E wole f'Oba, Ologo julo E korin ipaati ife Re Alabo wa ni, at'Eni Igbani O n gbenu ogo, Eleru ni iyin E so tipa Re, e so t'ore Re 'Mole laso Re, gobi Re orun B'ara ti n san ni keke ibinu Re Ipa ona ni a ko si le mo Aye yii pelu ekun re gbogbo Olorun, agbara Re lo da won O fi idi re mule, ko si le yi O si f'okun se oja igbaya re Itoju Re wa lara gbogbo won Ninu afefe, ninu imole Itoju Re wa nin'odo ti o n san O si wa ninu iri ati ojo Awa erupe, aw'alailera 'Wo la gbekele, O ki o da ni Anu Re ronu, o si le de opin Eleda, Alabo, Olugbala wa. 'Wo Alagbara, Onife julo B'awon angeli, ti nyin O loke Be lawa eda Re, niwon ta le se A o ma juba Re, a o ma yin O Oh, worship the King, all-glorious above, Oh, gratefully sing His pow’r and His love; Our Shield and Defender, the Ancient of Days, Pavilioned in splendor, and girded with praise. Oh, tell of His might, oh, sing of His grace, Whose r

E FI IYIN FUN OLORUN

Text: Thomas Ken E fi iyin fun Olorun E yin, eyin eda aye E yin eyin eda orun Yin Baba, Omo on Emi. Praise God, from whom all blessings flow; Praise Him, all creatures here below; Praise Him above, ye heav’nly host; Praise Father, Son, and Holy Ghost! Praise God the Father who’s the source; Praise God the Son who is the course; Praise God the Spirit who’s the flow; Praise God, our portion here below!

EYIN TE FE OLUWA

Text: Isaac Watts Eyin t'e fe Oluwa E fi ayo yin han E jumo ko orin didun/2x K'e si y'ite na ka/2x A n yan lo si Sion Sion t'o dara julo A n yan goke lo si Sion Ilu Olorun wa Awon ti ko korin Ni ko m'Olorun wa Sugbon awa omo Oba/2x Yio so ayo won ka/2x Oke Sion n mu Egberun adun wa Ki a to de gbangba orun/2x Pelu ita wura/2x Nje k'a maa korin lo K'omije gbogbo gbe A n yan n'ile Emmanuel/2x Saye didan loke/2x Source: Yoruba Baptist Hymnal #285 Come, ye that love the Lord, And let your joys be known; Join in a song with sweet accord, And thus surround the throne. We’re marching to Zion, Beautiful, beautiful Zion; We’re marching upward to Zion, The beautiful city of God. The sorrows of the mind Be banished from the place; Religion never was designed To make our pleasures less. Let those refuse to sing, Who never knew our God; But children of the heav’nly King May speak their joys abroad. The men of grace hav

FREE MUSIC DOWNLOAD

Hi friends, I just released three singles. You can download them free of charge from this link:   www.reverbnation.com/ preciousay

ISUN KAN WA

William Cowper, 1731-1800 Isun kan wa to kun feje, O yo niha Jesu. Elese mokun ninu re, O bo ninu ebi. Gba mo figbagbo risun naa, Ti n san fun ogbe Re, Irapada dorin fun mi Ti n o ma ko titi. Ninu orin to dun ju lo, Lemi o korin Re: 'Gba t'akololo ahon yii Ba dake niboji. Mo gbagbo p'O pese fun mi (Bi mo tile saiye) Ebun ofe ta feje ra, Ati duru wura. Duru ta towo'Olorun se, Ti ko ni baje lai: T'a o ma fi yin Baba wa, Oruko Re nikan. Source: YB Hymnal #232 There is a fountain filled with blood, Drawn from Immanuel’s veins, And sinners plunged beneath that flood Lose all their guilty stains: The dying thief rejoiced to see That fountain in His day; And there may I, though vile as he, Washed all my sins away: Dear dying Lamb, Thy precious blood Shall never lose its pow’r, Till all the ransomed church of God Are safe, to sin no more: E’er since by faith I saw the stream Thy flowing wounds supply, Redeeming love has been