Posts

Wa Obirin E Ko

Wa obirin, e ko Orin iye nipa Olugbala, Krist' 'Mole Olorun Krist' to jinde nipa, Krist' t'O de yin lade, Oun ni k'eyin. E ko awon 'mode Ati arabinrin Nile gbogboFun awon elese Fawon alailera Ateni okunkun Magbadura. Sise pelu 'gboya Ojumo fere mo Eni ife 'Rawo yo tan fun yin Inu yin yo si dun Ati nipa 'fe Re E ma reti. 'Gbati' kore ba de Aka Oluwa wa Yio kun pupo 'Reti Onirele Krist' ti gbogbo wa n wa, Krist' yo fun yin lere Pelu ayo Come, women, wide proclaim Life through your Savior slain; Sing evermore. Christ, God’s effulgence bright, Christ, who arose in might, Christ, who crowns you with light, Praise and adore. Come, clasping children’s hands, Sisters from many lands, Teach to adore. For the sin sick and worn, The weak and overborne, All who in darkness mourn, Pray, work, yet more. Work with your courage high, Sing of the daybreak nigh, Your love outpour. Stars shall

Jesu Fe K'emi Je 'mole

Nellie Talbot Jesu fe k'emi je 'mole Ki n tan lojoojumo Nibi gbogbo ki n le wun Oun, Nile, ni skul, lode. Refrain: Imole, imole, Jesu fe kemi je 'mole Imole, imole, Lemi yo je fun Jesu. Jesu fe ki emi feran, Gbogb'ohun ti mo ri, Ki n fi itara atayo, Tomode Re le je. Mo le semole fun Jesu, Bi mo ba gbiyanju; Ki n si sin Oun nigba gbogbo, Ki n ba Oun gbe orun. Source: Yoruba Baptist Hymnal #642 Jesus wants me for a sunbeam, To shine for Him each day; In every way try to please Him, At home, at school, at play. A sunbeam, a sunbeam, Jesus wants me for a sunbeam; A sunbeam, a sunbeam, I’ll be a sunbeam for Him. Jesus wants me to be loving, And kind to all I see; Showing how pleasant and happy His little one can be. I will ask Jesus to help me To keep my heart from sin, Ever reflecting His goodness, And always shine for Him. I’ll be a sunbeam for Jesus; I can if I but try; Serving Him moment by moment, Then live with Him on h

Itan Kan Wa Fawon Orile

H. Ernest Nichol, 1896 Itan kan wa fawon orile Ti yo tun okan won se Itan otito, ti o si dun Itan alafia, oun'mole, Itan alafia, oun'mole. Refrain: Tori okunkun yo di oye Oye yo dosan gangan Ijoba nla Krist' yo gba aye 'Joba ife ati'mole A lorin kan ko f'orilede, Ti wo gbokan won s'Oluwa, Orin ta fi segun Esu, A o se oko, a o si run'da, A o se oko, a o si run'da. A ni ise kan je forile-ede, P'Oluwa to joba loke, Ti ran 'Mo Re lati gba wa la, O fi han wa pe 'Fe l'Olorun Pe Ife ni Olorun. A l'Olugbala kan fi han 'raye, En' t'O koja nu 'banuje, Ki gbogbo eniyan agbaye Le gb' otito oro Olorun, Le gb' otito oro Olorun. Source: Yoruba Baptist Hymnal #642 We’ve a story to tell to the nations, That shall turn their hearts to the right, A story of truth and mercy, A story of peace and light, A story of peace and light. For the darkness shall turn to dawning, And the dawni

Gbo Ohun Jesu Ti N Ke Pe

Author: Daniel March , 1868. Gbo ohun Jesu ti n ke pe, Tani yoo sise loni? Oko pon pupo fun 'kore, Tani yi o lo ka a? Kikankikan l'Oluwa npe Ebun nla lo fi fun o. Tani yo fayo dahun pe, "Emi ni'i ran mi, ran mi." Biwo ko le la okun lo, Lati wa 'won keferi, O le ri won nitosi re, Won wa lenu ona re; Bo ko le fi wura tore, O le fi baba tore, Die to si se fun Jesu, 'Yebiye ni loju Re. Bo ko le soro b'angeli, Bo ko le wasu bi Paul' Iwo le so tife Jesu, O le so ti iku re; Biwo ko le ji elese Ninu ewu idajo, 'Wo le ko awon omode Li ona t'Olugbala. Biwo ko le kagbalagba, Krist' Olusaguntan ni, "Bo awon od'-aguntan Mi Gbe ounje ti won lodo," O le je pe awon 'mode To ti fi owo re to, Ni yoo wa larin oso re Gbat'o ba de'le rere. Ma jek'eniyan gbo wipe, "Ko si nkan temi le se," Nigba twon keferi nku, Ti Oluwa si n pe o, Fayo gba ise t'O pe o Kise Re je ayo r

Mo J'alejo Nihin

Author: Elijah T. Cassel (1902) Mo j’alejo nihin, 'nu ile ajeji, Ile mi jin rere, lor'ebute wura; Lati je iranse n'koja okun lohun Mo n sise nihin f'Oba mi. Refrain: Eyi nise ti mo wa je, 'Se tawon angel' nko lorin E b'Olorun laja l'Oluwa Oba wi E ba Olorun yin laja. Eyi lase Oba, keniyan n'bi gbogbo Ronupiwada kuro ninu 'dekun ese, Awon to ba gboran yio joba pelu Re, Eyi nise mi f'Oba mi. Ile mi dara ju petele Sharon lo, Nibiti 'ye ainipekun atayo wa; Ki n so fun araye, bi won se lee gbebe Eyi nise mi f'Oba mi. Source: Yoruba Baptist Hymnal #23 I am a stranger here, within a foreign land; My home is far away, upon a golden strand; Ambassador to be of realms beyond the sea, I’m here on business for my King. Refrain This is the message that I bring, A message angels fain would sing: “Oh, be ye reconciled," Thus saith my Lord and King, “Oh, be ye reconciled to God." This is the King’s co

Mo Ti N Bese Rin Tipe

Author Unknown Mo ti n bese rin tipe Pin wa niya Oluwa Ore 'parun ni tire Gba mi Jesu, mo segbe. Ko sanfani ti mo ri Lara ati lokan mi, Gbogbo re lo dibaje Jesu gba mi, mo segbe. Moriye nin'oro Re Ibagbe Re si wu mi, Ese di mi mu sinsin, Gba mi Jesu, jo gba mi. O ha dake ki n segbe, Nitori ailera mi? O ha jowo mi fese? Ka ma ri, Jesu gba mi. Iwo to rinu, rode, Iyanju mi han si O, O mo bi mo ti n ja to, O romije 'koko mi. Ese fi ewon de mi, Da mi, Oluwa da mi, Iwo ni n o sin titi, Jesu Olugbala mi. I have walk'd with sin so long, Seperate us, Saviour, Lord Friend of destruction is he Save me Jesus or I die There's no benefit I find Within my heart and body All of them are quite corrupt Save me Jesus or I die I find life within Thy word Thy communion is so sweet Sin doth hold me fast, O Lord Save me Jesus, do save me Will Thou silently watch me Till I die 'cause of weakness Will Thou leave me unto sin God forbi

Aigbagbo Bila

Author:  John Newton Aigbagbo bila! Temi l'Oluwa Oun o si dide fun igbala mi, Ki n sa ma gbadura, Oun o se 'ranwo: 'Gba Krist' wa lodo mi, ifoya ko si. Bona mi ba su, Oun l'O sa n to mi, Ki n sa gboran sa, Oun o si pese; Biranlowo eda gbogbo ba saki, Oro tenu Re so yo bori dandan. Ife to n fi han, ko je ki n ro pe, Yo fi mi sile ninu wahala; Iranwo ti mo si n ri lojojumo, O n ki mi laya pe emi o la a ja. Emi o se kun tori iponju, Tabi irora? O ti so tele! Mo moro Re pawon ajogun 'gbala, Wo ko le sai koja larin wahala. Eda ko le so kikoro ago T'Olugbala mu kelese le ye; Aye Re tile buru ju temi lo, Jesu ha le jiya, kemi si ma sa. Nje bohun gbogbo ti n sise ire, Adun nikoro, ounje li oogun; Boni tile koro, sa ko ni pe mo, Gbana orin 'segun yio ti dun to! Source: Yoruba Baptist Hymnal #330 Begone, unbelief;  my Savior is near, and for my relief  will surely appear; by prayer let me wrestle,  and he will perform; with