Gbo 'Gbe Ayo/Hark the Glad Sound
Philip Doddridge, 1702-1751 Gbo 'gbe ayo! Oluwa de, Jesu t' a seleri; Ki gbogbo okan mura de, K' ohun mura ko ' rin O de lati t' onde sile, L' oko eru Esu; 'Lekun 'de fo niwaju Re, Sekeseke 'rin da. O delarin 'baje aiye Lati tan 'mole Re, Lati fun awon afoju N' iriran f' oju won. O de! 'Tinu f' okan 'rora, Iwosan f' agbogbe; O de pel' opo 'sura Re Fun awon talaka. Hosanna wa, Oba 'lafia Ao kede bibo Re; Gbogbo orun y'o ma korin Oruko t' a feran. Hark the glad sound! The Savior comes, The Savior promised long; Let every heart prepare a throne And every voice a song. He comes the prisoners to release, In Satan's bondage held. The gates of brass before Him burst, The iron fetters yield. He comes from thickest films of vice To clear the mental ray And on the eyeballs of the blind To pour celestial day. He c