SI PEPE OLUWA

Author Unknown
Si pepe Oluwa,
Mo mu 'banuje wa;
'Wo ki o fanu tewogba
Ohun alaiye yi?

Kristi Odaguntan
Ni igbagbo mi n wo;
'Wo le ko'hun alaiye yi?
'Wo o gba ebo mi.

Gba ti Jesu mi ku,
A te ofin lorun;
Ofin ko ba mi leru mo,
Tori pe Jesu ku.
To the altar of my Lord,
I bring all my sorrows,
Can your mercy kindly accept me,
Even this living soul?

Jesus Christ the Lamb of God,
All time depends on You,
Will You reject this my living soul?
Sacrifice Thou accept

When Christ died for me,
The fulfilment of law
The law has no more power on me,
Jesus has died for me.

Source: Hymnaro #590
Aroyehun ©2013

Comments

Popular posts from this blog

JESU NI BALOGUN OKO

E BA WA YIN OLUWA, ALLELUYA!

Mo N Tesiwaju Lona Na