IWO HA N BERU P'OTA YOO SEGUN

Words: Ada Blenkhorn

Iwo ha n beru p'ota yoo segun?
Ookun su lode osi su ju ninu?
Si ferese ati ilekun sile
Je ki 'ran oorun wole

Refrain:
Je ki 'ran oorun wole/2x
Si ferese ati ilekun sile
Je ki 'ran oorun wole.

Igbagbo re n kere 'nu 'ja tiwo fe?
Olorun ko ha gbo adura re bi?
Si ferese ati ilekun sile
Je ki 'ran oorun wole

Iwo fe fi ayo lo soke orun?
Ko si oorun mo bi ko se imole?
Si ferese ati ilekun sile
Je ki 'ran oorun wole
Do you fear the foe will in the conflict win?
Is it dark without you—darker still within?
Clear the darkened windows, open wide the door,
Let a little sunshine in.

Let a little sunshine in,
Let a little sunshine in;
Clear the darkened windows,
Open wide the door,
Let a little sunshine in.

Does your faith grow fainter in the cause you love?
Are your prayers unanswered by your God above?
Clear the darkened windows, open wide the door,
Let a little sunshine in.

Would you go rejoicing in the upward way,
Knowing naught of darkness, dwelling in the day?
Clear the darkened windows, open wide the door,
Let a little sunshine in.


Comments

Popular posts from this blog

JESU NI BALOGUN OKO

E BA WA YIN OLUWA, ALLELUYA!

Mo N Tesiwaju Lona Na