Itan Iyanu Tife

Author: J. M. Driver (1892)
Itan iyanu tife! So fun mi leekan si,
Itan iyanu tife! Ti n dun leti kikan!
Awon angeli rohin re, awon oluso si gbagbo,
Elese iwo ki yoo gbo, itan iyanu tife?


Iyanu!/3X
Itan iyanu tife!

Itan iyanu tife! Biwo tile sako
Itan iyanu tife!Sibe o n pe loni;
Latori oke Kalfari, lati orisun Krystali;
Lat isedale aye; Itan iyanu tife!

Itan iyanu tife! Jesu ni isimi;
Itan iyanu tife! Fun awon olooto,
To sinmi nilu nla orun, pel' awon to saju wa lo;
Won n kan orin ayo orun: Itan iyanu tife!



Wonderful story of love;
Tell it to me again;
Wonderful story of love;
Wake the immortal strain!
Angels with rapture announce it,
Shepherds with wonder receive it;
Sinner, oh, won’t you believe it?
Wonderful story of love.

Wonderful! Wonderful!
Wonderful, wonderful story of love.

Wonderful story of love;
Though you are far away;
Wonderful story of love;
Still He doth call today;
Calling from Calvary’s mountain,
Down from the crystal-bright fountain,
E’en from the dawn of creation,
Wonderful story of love.

Wonderful story of love;
Jesus provides a rest;
Wonderful story of love;
For all the pure and blest,
Rest in those mansions above us,
With those who’ve gone on before us,
Singing the rapturous chorus,
Wonderful story of love.


Comments

Popular posts from this blog

JESU NI BALOGUN OKO

Olori Ijo T'orun

E BA WA YIN OLUWA, ALLELUYA!