Ma Wole, Jesu Ta N Reti

Ma wole, Jesu ta n reti,
Ta bi lati gba ni la!
Gba wa low'ese ate'eru;
Ka ri'sinmi ninu Re.

Ipa ati'tunu Israel',
Ireti awon mimo;
Olufe gbogbo orile,
Ayo okan ti n reti.

A bi O lati gbeda la,
Eniyan--sugbon Olorun--
Lati joba lai ninu wa,
Mu 'joba rere re wa.

Nipa Emi Re to wa lai,
Nikan joba ninu wa;
Nipa 'toye Re to po to
Gbe wa site ogo Re.
Long expected, our Lord Jesus,
Born to give us salvation,
Redeem us from fear and sin
Give us peace eternally/2x

Pow’r, peace and joy for Israel,
The hope of righteous men,
Lover of the entire nations;
Joy for the expectant souls/2x

Born to give us salvation,
God born of human flesh
To reign in heart for ever,
Send down Thou good governance/2x

By the Spirit forever more,
Reign forever in our souls
By the great mercies forever,
Reign with You all ever more /2x

Source: Hymnaro #88
Aroyehun ©2013

Comments

Popular posts from this blog

JESU NI BALOGUN OKO

Olori Ijo T'orun

E BA WA YIN OLUWA, ALLELUYA!