OJO NLA
Words: Philip Doddridge, refrain from Wesleyan Sacred Harp Ojo ayo l’ ojo ti mo Yan O, 'Wo Olugbala mi; O to ki okan mi ko yo, K’o si sayo re kakiri. Ojo nla l’ ojo na! Ti Jesu we ese mi nu O ko mi ki n ma gbadura Ki nma sora ki nsi ma yo Ojo nla l’ ojo na! Ti Jesu we ese mi nu. A ti pari ise nla naa Emi t'Oluwa O'n temi O fa mi mo si tele O Mo yo lati gba ipe naa. Simi aisokan, okan mi, Simi lori ipinnu yi; Mo ripa to lola nibi, Ayo orun kun mi laya. Orun giga to gbeje mi, Yoo gbo lotun lojojumo, Titi n o fi fibukun fun, Idapo yi loju iku. O happy day, that fixed my choice On Thee, my Savior and my God! Well may this glowing heart rejoice, And tell its raptures all abroad. Happy day, happy day, When Jesus washed my sins away! He taught me how to watch and pray, And live rejoicing every day: Happy day, happy day, When Jesus washed my sins away! O happy bond, that seals my vows To Him Who merits all my love! Let cheerful an...