Posts

Showing posts from April, 2015

Ji Okan Mi Ba Oorun Ji

Words: Thomas Ken Ji okan mi ba oorun ji, Mura si ise ojo re; Mase ilora, ji kutu, Ko san gbese ebo ooro. Ogo fun Enit'o so mi, To tu mi lara loj'oorun; Oluwa ijo mo ba ku, Ji mi saye ainipekun. Oluwa mo tun eje je, Tu ese ka biri ooro; So akoronu mi oni, Si f'Emi Re kun inu mi. Oro atise mi oni, Ki won le ri bi eko Re; Kemi fi ipa mi gbogbo Sise rere fun ogo Re. Source: YB Hymnal #47 Awake, my soul, and with the sun Thy daily stage of duty run; Shake off dull sloth, and joyful rise, To pay thy morning sacrifice. Thy precious time misspent, redeem, Each present day thy last esteem, Improve thy talent with due care; For the great day thyself prepare. By influence of the Light divine Let thy own light to others shine. Reflect all Heaven’s propitious ways In ardent love, and cheerful praise. In conversation be sincere; Keep conscience as the noontide clear; Think how all seeing God thy ways And all thy secret thoughts surveys. Wak...

Isun Kan Wa To Kun Feje

William Cowper, 1731-1800 Isun kan wa to kun feje, O yo niha Jesu. Elese mokun ninu re, O bo ninu ebi. Gba mo figbagbo risun naa, Ti n san fun ogbe Re, Irapada dorin fun mi Ti n o ma ko titi. Ninu orin to dun ju lo, Lemi o korin Re: 'Gba t'akololo ahon yii Ba dake niboji. Mo gbagbo p'O pese fun mi (Bi mo tile saiye) Ebun ofe ta feje ra, Ati duru wura. Duru ta towo'Olorun se, Ti ko ni baje lai: T'a o ma fi yin Baba wa, Oruko Re nikan. Source: YB Hymnal #232 There is a fountain filled with blood, Drawn from Immanuel’s veins, And sinners plunged beneath that flood Lose all their guilty stains: The dying thief rejoiced to see That fountain in His day; And there may I, though vile as he, Washed all my sins away: Dear dying Lamb, Thy precious blood Shall never lose its pow’r, Till all the ransomed church of God Are safe, to sin no more: E’er since by faith I saw the stream Thy flowing wounds supply, Redeeming love has been...

Laifoya Lapa Jesu

By Frances J. Crosby , 1868 Laifoya lapa Jesu, Laifoya laya Re Labe ojiji 'fe Re Lokan mi yo sinmi. Gbo ohun angeli ni, Orin won deti mi, Lati papa ogo wa, Lati okun Jaspi. Refrain: Laifoya lapa Jesu Laifoya laya Re Labe ojiji 'fe Re Lokan mi yo sinmi. Laifoya lapa Jesu Mo bo low'aniyan, Mo bo lowo idanwo, Ese ko nipa mo, Mo bo lowo 'banuje, Mo bo lowo eru O ku idanwo die! O k'omije die! Jesu abo okan mi, Jesu ti ku fun mi, Apata ayeraye Lemi o gbekele, Nihin lemi o duro Tit'oru yo koja, Titi n o fi rimole Ni ebute ogo. Source: Yoruba Baptist Hymnal #254 Safe in the arms of Jesus, Safe on His gentle breast; There by His love o’ershaded, Sweetly my soul shall rest. Hark! ’tis the voice of angels Borne in a song to me, Over the fields of glory, Over the jasper sea. Refrain: Safe in the arms of Jesus, Safe on His gentle breast; There by His love o’ershaded, Sweetly my soul shall rest. Safe in the arms of Jes...

Ninu Gbogbo Ewu Oru

Image
Thomas Kelly, 1769-1855 Ninu gbogbo ewu oru, Oluwa l'O n so wa; Awa si tun rimole yii, A tun te ekun ba. Oluwa pa wa mo loni, Fi apa Re so wa, Kiki awon t'Iwo pa mo, Lo n yo ninu ewu. Koro wa ati iwa wa, Wipe, Tire l'awa; To bee kimole otito Le tan loju aye. Ma je ka pada lodo Re, Olugbala owon; Titi a o foju wa ri Oju Re nikehin. Source: Yoruba Baptist Hymnal #232 Through all the dangers of the night, Preserv'd, O Lord! By thee; Again we hail the cheerful light, Again we bow the knee. Preserve us, Lord! throughout the day, And guide us by thy arm; For they are safe, and only they, Whom thou preserv'st from harm. Let all our words and all our ways, Declare that we are thine, That so the light of truth and grace Before the world may shine. Let us ne'er turn away from thee; Dear Saviour, hold us fast, Till with immortal eyes, we see Thy glorious face at last.