Iwo Ti Gbogbo Eda N Sin

Iwo ti gbogbo eda nsin
L' ara erupe yi,
Bi O tit obi to l'aiye!
B' ogo Re ti po to!
 
Nigbati mo f' iyanu wo
Ogo 'se Re l' oke,
Osupa ti njoba l' oru,
At' irawo tin tan.
 
Oluwa kil' enia ti
'Wo fe ma ronu re?
Tab' iran re t' Iwo 'ba ma
S ore to to yi fun?
 
Iwo ti gbogbo eda nsin
L' ara erupe yi,
Bi O tit obi to l' aye!
B' ogo Re ti po to.

Comments

Popular posts from this blog

JESU NI BALOGUN OKO

E BA WA YIN OLUWA, ALLELUYA!

Mo N Tesiwaju Lona Na