A Fiyin Aiku Fun
Writer: Isaac Watts
| A f' iyin aiku fun 
'Fe Olorun Baba, Fun itunu t' aiye, At' ireti t' orun: O ran 'Mo Re aiyeraiye Lati ku fun ese t' a da. 
T' Olorun Omo ni 
Ogo lailai pelu, 
T' o f' eje Re ra wa 
N'nu egbe ainipekun : 
O ye, O joba nisiyi, 
O si nri eso iya Re. 
Wole fun oruko, 
Olorun emi lai, 
Enit' agbara Re 
So elese d' aye: 
On l' o par' ise 'gbala wa, 
L' o si f' ayo orun k' okan. 
'Wo Olodumare, 
L' ola ye titi lai, 
Eni Metalokan, 
T' O tobi, t' O l' ogo: 
Nibiti ipa ero pin, 
'Gbagbo bori, ife sin yin. Source: Baptist Hymnal #158 | 
 | 
 
Comments
Post a Comment