Halleluyah, Halleluyah
Writer: Christopher Wordsworth (1807-1885), 1862
Halleluyah, Halleluyah,
E gbe ohun ayo ga, E korin inudidun, K' e si yin olorun wa, Enit'a kan m'agbelebu, T' o jiya fun ese wa; Jesu Kristi Oba ogo Jinde kuro n'nu oku.
Irin idabu se kuro
Kristi ku, O sit un ye,
O mu iye at aiku
Wa l'oro ajinde Re;
Krist' ti' segun, awa segun
Nipa agbara nla Re,
Awa o jinde pelu Re,
A o ba wo 'nu ogo.
Kristi jinde, akobi ni
Ninu awon t' o ti sun,
Awon yi ni y' o ji dide,
Ni abo Re ekeji;
Ikore ti won ti pon tan
Nwon nreti Olukore,
Eniti y'o mu won kuro,
Ninu isa oku won.
Awa jinde pelu Kristi
T'O nfun wa l' ohun gbogbo
Ojo, iri, ati ogo
To ntan jade l' oju Re;
Oluwa b' a ti wa l'aiye,
Fa okan wa s'odo Re,
K'awon maleka saw a jo,
Ki nwon ko wa d,odo Re.
Halleluyah, Halleluyah!
Ogo ni fun Olorun;
Halleluyah f' Olugbala
Enit' Osegun iku.
Halleluyah f' Emi Mimo,
Orison 'fe, 'wa mimo,
Halleluyah, Halleluyah,
F' Olorun Metalokan.
Source: Baptist Hymnal #124 | Alleluia, alleluia! sing to God a hymn of gladness, sing to God a hymn of praise. He, who on the cross a victim, for the world's salvation bled, Jesus Christ, the King of glory, now is risen from the dead. Now the iron bars are broken, Christ from death to life is born, glorious life, and life immortal, on this holy Easter morn. Christ has triumphed, and we conquer by his mighty enterprise: we with him to life eternal by his resurrection rise. Christ is risen, Christ, the first fruits of the holy harvest field, which will all its full abundance at his second coming yield: then the golden ears of harvest will their heads before him wave, ripened by his glorious sunshine from the furrows of the grave. Christ is risen, we are risen! Shed upon us heavenly grace, rain and dew and gleams of glory from the brightness of thy face; that we, with our hearts in heaven, here on earth may fruitful be, and by angel hands be gathered, and be ever, Lord, with thee. Alleluia, alleluia! Glory be to God on high; Alleluia! to the Savior who has gained the victory; Alleluia! to the Spirit, fount of love and sanctity: Alleluia, alleluia! to the Triune Majesty. |
To God be the Glory Yoruba Lyrics
ReplyDeleteOgo ni f'Oluwa t'o se ohun nla
Ogo ni f'Oluwa t'o se ohun nla
Ife lo mu k'O fun wa ni omo re
Eni t'o f' emi re lele f'ese wa
To si Ilekun iye sile fun wa.
Yin Oluwa, Yin Oluwa
Fiyin fun Oluwa
Yin Oluwa, Yin Oluwa
E yo niwaju re
K'a to Baba wa lo l'oruko Jesu
Jek'a jo f'ogo fun onise 'yanu
Irapada kikun ti eje re ra
F'enikeni t'o gba ileri re gbo
Enit'o buruju b'oba le gbagbo
Lojukanna yo ri idariji gba
O s'ohun nla fun wa, o da wa l'ola
Ayo wa di kikun ninu Omo re,
Ogo ati ewa irapada yi,
Y'o ya wa lenu 'gbata ba ri Jesu.