Krist' Oluwa Ji Loni
Writer: Charles Wesley
Krist' Oluwa ji loni, - Halleluyah,
Eda at' Angeli nwi - Hal. Gb' ayo at' isegun ga - Hal. K' orun at' aiye gberin! - Hal.
Ise ti idande tan; - Hal.
O jija, O ti segun; - Hal.
Wo, 'ponju orun koja - Hal.
Ko wo sinu eje mo - Hal.
Lasan n' iso at' ami, - Hal.
Krist' woo run apadi; - Hal
Lasan l' agbara iku, - Hal.
Krist, si Paradise. - Hal.
O tun wa, Oba ogo: - Hal.
"Iku itani re wa?" - Hal.
Lekan l' O ku k' O gba wa, - Hal.
"'Boji, isegun re wa?" - Hal.
E je k' awa goke lo, - Hal.
Sodo Kristi Ori wa, - Hal.
A sa jinde pelu Re, - Hal.
Bi a ti ku pelu Re. - Hal.
Oluwa t' aiye t' orun, - Hal.
Tire ni gbogbo iyin, - Hal.
A wole niwaju Re - Hal.
'Wo Ajinde at' Iye. - Hal.
Source: Baptist Hymnal #118 |
|
Comments
Post a Comment