Niboji la t'E si/ Low In The Grave He Lay
Author: Robert Lowry Niboji la t'E si Jesu Olugbala Jesu Oluwa mi 'Reti ojo naa Refrain: Nisa oku, Jesu ji! Pelu 'segun lor' awon ota Re O jinde pelu 'segun lor' okunkun O joba titi pel'awon eni mimo Jesu ji, Jesu ji, Halleluyah, O jinde! Lasan won ṣọ 'busun Rẹ Jesu Olugbala Lasan won di oku Jesu Oluwa! Iku ko le gbe E de Jesu Olugbala! Jesu Oluwa mi Fo 'lekun irin Translation by Biola Dada (Mrs) & Lanre Oyedokun, August 2016 Low in the grave He lay, Jesus my Savior, waiting the coming day, Jesus my Lord! Refrain: Up from the grave He arose; with a mighty triumph o'er his foes; He arose a victor from the dark domain, and He lives forever, with his saints to reign. He arose! He arose! Hallelujah! Christ arose! Vainly they watch His bed, Jesus my Savior, vainly they seal the dead, Jesus my Lord! Death can...