Posts

Showing posts from March, 2018

Ohun Ipe Kan Ti Oke Petele Wa

Ohun ipe kan ti oke petele wa, S' olotito, 'lotito, 'lotito si Krist, Oke gba orin na, gege b'o ti ndun lo, T' olotito, 'lotito, A! 'lotito si Krist. Refrain Lo si isegun, lo si isegun, Ni ase Balogun wa, Ao lo li ase Re laipe ao gba 'le na Pel' otito, 'lotito, A! 'lotito si Krist. Enyin akin e gbo, iro to mi aiye, S' olotito, 'lotito, 'lotito si Krist, E dide e sise, kede otito na, T' olotito, 'lotito, A! 'lotito si Krist. Wa dapo m' egbe wa, ao Omiran na, S' olotito, 'lotito, 'lotito si Krist, Ao fun ipe ogun, s' ori ogun Esu, T' olotito, 'lotito, A! 'lotito si Krist. A fi agbara wa le Oluwa lowo, S' olotito, 'lotito, 'lotito si Krist, Ao kede 'gbala Re yi gbogbo aiye ka, T' olotito, 'lotito, A! 'lotito si Krist. Source: Yoruba Baptist Hymnal #660

Otito Re Tobi / Great is Thy faithfulness

Author:  Thomas Obadiah Chisholm Otito Re tobi, Bab' Olorun mi, Ko si ayidayida lodo Re; 'Wo ko yi pad' anu Re ko kuna ri, Bi O ti wa, beeni O wa titi. Egbe Otito Re tobi, o tito Re tobi. Laraaro anu tuntun ni mo n ri, Gbogb' ohun mo fe lowo Re ti pese, Otito Re tobi pupo si mi Igba oru, oye, oj' ati 'kore, Orun, osupa, 'rawo lona won Dapo m'eda gbogbo ni ijeri si Otito nla, anu at' ife Re. 'Dariji ese, alafia to daju, 'Walaye Re to n 'tunu to n dari; Agbara fun oni, ireti f' ola, Ibukun ainiye si je temi. Great is Thy faithfulness, o Lord my Father,  There is no shadow of turning with Thee;  Thou changeth not, Thy compassionate they fail not,  As Thou hast been, Thou forever wilt be.  Refrain   Great is thy faithfulness/2x Morning by morning new mercies I see All I have needed Thy hand hath provided. Great is thy faithfulness Lord unto me Summer and winter and s...

Gb' ope mi, Oluwa

Gb' ope mi, Oluwa, Lat' okan l' o ti wa, Iwo t' O gba die opo, K'yo kegan 'more mi. Tire ' eran gbogbo, Ti nfo lori oke; Gbogbo 'sura t' o wa l' odo, At' oro 'nu ile. Kini 'ba damu Re? Kil' O fe ti ko si? Apakan ohun t' O fun mi Ko mo mu wa fun O? Ohun idupe ko L' O fe, bi okan wa; Ko s' ohun t' o te O lorun Bi okan imore. Eyi ni mo mu wa, - Okan t' o kun fu je 'fe, O n' iyi l' oju Re j' opo Ore ode okan.