Otito Re Tobi / Great is Thy faithfulness
Author: Thomas Obadiah Chisholm
Read story behind hymn here.
Otito Re tobi, Bab' Olorun mi,
Ko si ayidayida lodo Re; 'Wo ko yi pad' anu Re ko kuna ri, Bi O ti wa, beeni O wa titi. Egbe Otito Re tobi, otito Re tobi.
Laraaro anu tuntun ni mo n ri,
Gbogb' ohun mo fe lowo Re ti pese,
Otito Re tobi pupo si mi
Igba oru, oye, oj' ati 'kore,
Orun, osupa, 'rawo lona won
Dapo m'eda gbogbo ni ijeri si
Otito nla, anu at' ife Re.
'Dariji ese, alafia to daju,
'Walaye Re to n 'tunu to n dari;
Agbara fun oni, ireti f' ola,
Ibukun ainiye si je temi.
|
Refrain
Great is thy faithfulness/2x
Morning by morning new mercies I see
All I have needed Thy hand hath provided.
Great is thy faithfulness Lord unto me
Summer and winter and springtime and harvest,
Sun moon and stars in their courses above
Join with all nature in manifold witness,
To Thy great faithfulness mercy and love.
Pardon for sin and a peace that endureth,
Thine own dear presence to cheer and to guide;
Strength for today and bright hope for tomorrow,
Blessings all mine with ten thousand beside.
|
Read story behind hymn here.
Ki Oluwa ki o bukun fun ise takun takun ti e se lori oro orin yi. Amin
ReplyDeleteAmin Jesu. E see pupo.
DeleteGod bless you so much ma. Ese gan ni
ReplyDeleteAmen!
DeleteI so appreciate you, God bless you
ReplyDeleteAmen!
DeleteWow! God bless you for this awesome job. You are lifted in Jesus name. More auction to function.
ReplyDeleteAmen! Thank you, Tola.
DeleteESE pupo olorun yio bukun yin
ReplyDeleteI very happy I found this song Yoruba version
Amin!
DeleteEse Gan ni ti e pese Orin yi ni Ede Yoruba, o ma nru mi soke gidigidi ti mo ba nko Orin yi ni Ede abinibi mi. Otito oluwa yo tun fese mule ninu aye yin gidigidi. Amin.
ReplyDelete