Kábíyèsí O, Hòsánnà O

Author: Segun Roberts


Kábíyèsí o, hòsánnà o
Ẹ yin Jésù Kristì Ọba àìkú
Kabiyesi o, hosanna o
Ẹ yin Jésù Kristì Ọba àìkú

Ègbè
Ẹ gbé E ga, Ẹ yin Jésù o
Ẹ yin Jésù Kristì Ọba àìkú
[Repeat]

Wá ká yin Jésù, ará mi ò
Ọba mímọ́ Jésù, Ọba àìrí
Wá júbà Jésù Olúwa ò
Yin Elédùmarè Ọba àìkú

Ègbè

Ọbańgijì yé o, Olúwa ò
Wá gbọpẹ́ wá gba ìyìn àwa ọmọ Rẹ
Ángẹ́lì lọ́run ẹ bá wa yìn
Ẹ yin Jésù Krístì Ọba àìkú

Ègbè

Alelúyà sí Ọ Olúwà o
Ọpẹ́, ọlá, ìyìn sí Olùbùkún
Ho-hosanna, alelúyà o
Ẹ yin Jésù Krístì Ọba àìkú

Ègbè

Unquestionable God, hosanna to You
Praise Jesus Christ the immortal King
Unquestionable God, hosanna to You
Praise Jesus Christ the immortal King

Refrain
Lift Him up, oh now  praise Jesus
Praise Jesus Christ the immortal King

Come let’s praise Jesus o my brethren
Holy King Jesus, the immortal King
Come and worship Jesus the Lord
Praise the Almighty, the immortal King

Refrain

The Most Sovereign, O Lord our God
Come and receive the praises of Your children
Angels in heaven, help us to adore
Praise Jesus Christ the immortal King

Refrain

Hallelujah to You, o Lord our God
Thanks, honour and praises to the Blessed One
Hosanna, hallelujah oh
Praise Jesus Christ the immortal King

Refrain

Translated by Ayobami Temitope Kehinde, 10/18/2018

Comments

  1. Thank you for this translation. This song was on my heart this morning. I was about to give up on searching for the translation but I found ur page. Be blessed.

    ReplyDelete
  2. I used to hear this song, though never knew the meaning. Just saw myself singing and dancing this in my dream, that made me to start looking for the meaning. Thanks alot for the translations. I love you jesus, i love you my maker and i will forever praise Thee.

    ReplyDelete
  3. Wow, glory be to God in the highest!

    ReplyDelete
  4. Thank you for this, God bless you!!!

    ReplyDelete
  5. Our choir ministration this Sunday. Thank You t

    ReplyDelete

Post a Comment

Popular posts from this blog

JESU NI BALOGUN OKO

E BA WA YIN OLUWA, ALLELUYA!

Mo N Tesiwaju Lona Na